JSS3 Yoruba Scheme of Work

Download the Junior Secondary School 3 (JSS3) Unified Scheme of Work for Yoruba to serve as a guide for educators.

Home » JSS3 Scheme of Work » JSS3 Yoruba Scheme of Work

About JSS3 Yoruba Scheme of Work

Studying Yoruba in Junior Secondary School 3 (JSS3) provides students with a thorough understanding of the Yoruba language, literature, and culture, enhancing their linguistic proficiency and cultural awareness. 

 

Learning Yoruba improves students’ communication skills, critical thinking, and appreciation of their heritage. Proficiency in the language is key for excelling in the Basic Education Certification Examination (BECE), as it not only expands students’ knowledge but also reinforces their cultural identity, fostering a sense of pride and connection to their roots.

Assessment Guide

The crowning event for Jss3  and the Junior Secondary school as a whole is the Basic Education Certificate Examination (BECE) which is taken mid-third term. The assessment methods for Yoruba include written examinations, which may consist of multiple-choice questions, short-answer questions, and essay-type questions. These exams are conducted in a controlled environment to ensure fairness and integrity.

Furthermore, continuous assessment, which involves periodic tests, assignments, and projects conducted throughout the academic session, also contributes to the overall BECE assessment. This allows for an all-around evaluation of students’ performance and progress over time.

Download JSS3 Yoruba Scheme of Work

jss3-yoruba

Know what’s expected of you as an educator

Download the Unified Scheme of Work for JSS3 Yoruba

JSS3 First Term Scheme of Work for Yoruba

 NATIONAL ASSOCIATION OF PROPRIETORS OF PRIVATE SCHOOLS (NAPPS) SCHEMES OF WORK FOR JUNIOR SECONDARY SCHOOLS
 Yoruba Scheme of Work for Junior Secondary School 3(JSS3)
 ClassJ.S.S 3
 SubjectYoruba L2
 TermFirst Term
WeekTopicBreakdown
1ÀŚÀ: Ìśêdálê àti Ìtànkálê Ômô YorùbáÀKÓÓNÚ IŚË
a. Ìśêdálê Yorùbá láti õdõ Odùduwà
b. Àwôn ìlú tí ó jë ti Yorùbá
d. Orúkô àwôn ômô Odùduwà
2FÓNËTÍÌKÌ: Ìró Èdè YorùbáÀKÓÓNÚ IŚË
a. Álífábëêtì Yorùbá
b. Kíka álífábëêtì láti A – Y
d. Àlàyé lórí lëtà ńlá àti lëtà kékeré
e. Ìsõrí álífábëêtì èdè Yorùbá (B.a. köńsónáýtì àti fáwëlì àìránmúpè àti fáwëlì àránmúpè)
ç. Ìyàtõ láàrin álífábëêtì èdè Yorùbá àti èdè Gêësì.
3ÀŚÀ: ÌkíniÀKÓÓNÚ IŚË
a. Ìkíni ní onírúurú ìgbà àti àkókò (B.a. àárõ, õsán, alë, òru, ìyálêta, ààjìn abbl)
b. Ìkíni fún onírúurú ayçyç (Bí ìsômôlórúkô, ìgbéyàwó, ôlöjö ìbí, oyè jíjç, ìkíni fún aláboyún abbl). d. Ìkíni fún onírúurú iśë. Bí àpççrç: àgbê, ôdç, akõpç, onídìrí, aláró, awakõ, alágbêdç, babaláwo abbl.
4ÈDÈ: ÀkàyéÀKÓÓNÚ IŚË
a. Kíka àwôn ìtàn kéèkèèké ôlörõ geere àti ewì.
b. Títúmõ àwôn õrõ tí ó ta kókó inú àyôkà.
d. Ìbéèrè àti ìdáhùn lórí àyôkà.
5ÀŚÀ: Àśà Ìgbéyàwó Nílê YorùbáÀKÓÓNÚ IŚË
a. Ìtumõ àti oríśi ìgbéyàwó
b. Àwôn ìgbésê ìgbéyàwó bí i ìfojúsóde, alárinà, ìtôrô, ìjöhçn tàbí
ìśíhùn, ìdána abbl
d. Àwôn ohun èlò ìdána àti ìwúlò wôn.
6ÈDÈ: ÀkôtöÀKÓÓNÚ IŚË
a. Àtúnyêwò álífábëêtì èdè Yorùbá
b. ìtumõ àkôtö
d. sípëlì àtijö àti àkôtö òde òní
e. ìyàtõ láàrin sípëlì àtijö àti àkôtö òde òní.
i. Fáwëlì: aiye – ayé -yio – yóò
-enia – ènìyàn, abbl
ii. Köńsónáýtì: Oshogbo – Òśogbo, abbl
iii. Àmì ohùn: õgun – òógùn
-alãnu – aláàánú iv. Yíyán õrõ nídìí: ẹ – ç , ṣ – ś, ọ – ô
v. Pípín õrõ: wipe – wí pé -nigbati – nígbà tí
7LÍTÍRÈŚÕ: Lítírèśõ YorùbáÀKÓÓNÚ IŚË
a. Ìtumõ oríkì lítírèśõ
b. Êka lítírèśõ Yorùbá
i. Lítírèśõ Àpilêkô
ii. Lítírèśõ Alohùn
d. Ìsõrí Lítírèśõ àpilêkô
i. Àpilêkô ôlörõ geere
ii. àpilêkô ewì
iii. àpilêkô eré-onítàn
e. Ìsõrí lítírèśõ alohùn
i. ôlörõ geere
ii. ewì alohùn
iii. eré-oníśe
8LÍTÍRÈŚÕ: Òýkà YorùbáÀKÓÓNÚ IŚË
a. Òýkà Õödúnrún dé irínwó (300 – 400)
9ÈDÈ: Ìsõrí ÕrõÀKÓÓNÚ IŚË
a. õrõ-orúkô
b. õrõ aröpò- orúkô/ aröpò afarajorúkô
d. õrõ-ìśe
e. õrõ-àpèjúwe ç. õrõ-àpönlé
f. õrõ-atökùn
g. õrõ-àsopõ
10ÀŚÀ: Òwò Śíśe àti Ìpolówó ÔjàÀKÓÓNÚ IŚË
a. ìdí tí a fi ń polówó ôjà
b. bí a śe ń polówó kõõkan. Bí àpççrç; Ç fçran jêkô
d. ôgbön ìpolówó ôjà láyé àtijö àti lóde òní. Bí àpççrç: ìpolówó lórí
rédíò, tçlifísàn, ìwé ìròyìn, ìpàtç, ìkiri abbl.
11ÈDÈ: Ìśêdá Õrõ-OrúkôÀKÓÓNÚ IŚË
a. kí ni õrõ-orúkô?
b. oríśi õrõ-orúkô méjì: àìśêdá àti èyí tí a śêdá pêlú àpççrç.
d. Àlàyé kíkún lórí oríśiríśi õnà ìśêdá õrõ-orúkô pêlú àpççrç.
12ÈDÈ: Àròkô kíkôÀKÓÓNÚ IŚË
a. Àlàyé lórí àròkô kíkô
b. Oríśiríśi àròkô
d. Ìgbésê
13ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ 
14ÌDÁNWÒ 

 

JSS3 Second Term Scheme of Work for Yoruba

 TermSecond Term
WeekTopicBreakdown
1FÓNËTÍÌKÌ: Àwôn êyà ara fún ìró èdè pípèÀKÓÓNÚ IŚË
a. Àwôn êyà ara tí a fi ń pe ìró
b. Oríśi àfipè:
i. Àwôn êyà ara tí a lè fi ojú rí
ii. Àwôn êyà ara tí a kò lè fojú rí
iii. Àfipè àsúnsí
iv. Àfipè àkànmölê
2ÀŚÀ: Oyún níní àti ìtöjú AláboyúnÀKÓÓNÚ IŚË
a. Ìgbàgbö Yorùbá nípa àgàn, ômô bíbí àti àbíkú
b. Àwôn tí oyún níní wà fún (tôkôtaya)
d. Õnà tí a lè gbà dín bíbí àbíkú kù láwùjô
e. oríśiríśi jënótáìpù êjê tó wà àti àwôn tó lè fëra wôn.
ç. Aájò láti lè tètè lóyún – àýfààní kíkóraçni-níjàánu nípa ìbálòpõ
f. Bí a śe ń töjú aboyún látijô àti lóde òní:
Àtijö;  Oyún dídè, èèwõ aláboyún, àsèjç, àgbo abbl
Òde òní
 Oúnjç aśaralóore, lílô fún ìtöjú ní ilé ìwòsàn (ìbílê/ ìjôba) abbl
3ÈDÈ: ÌdámõÀKÓÓNÚ IŚË a. Dídá nýkan mõ ní ilé-êkö àti inú ilé.
b. Dárúkô àwôn ènìyàn àti bí wön śe jë sí ara wôn
d. Dárúkô díê nínú àwôn êyà ara wa; ojú, imú, ôwö, çsê abbl
4ÀŚÀ: Àkókò, ìgbà àti ojú ôjöÀKÓÓNÚ IŚË
a. Ôjö tó wà nínú õsê
b. orúkô àwôn ośù nínú ôdún
d. Sísô iye agogo tó lù
5ÈDÈ: Lëtà KíkôÀKÓÓNÚ IŚË
a. Oríśi lëtà: lëtà gbêfê àti àìgbagbêfê
b. Ìyàtõ àárin wôn
d. ìlànà kíkô lëtà gbêfê
– àdírësì, déètì, kíkô õrõ inú lëtà kí a sì
pín-in sí ègé afõ bí ó ti yç.
– àsôkágbá/ àgbálôgbábõ/ ìgúnlê
e. ìlapa kíkô lëtà àìgbagbêfê
– Àdírësì – Déètì
– Àkôlé
– Õrõ inú lëtà tí a pín sí ègé afõ bí ó ti yç.
6LÍTÍRÈŚÕ: Ìwé Kíkà (Àśàyàn Ìwé ìtàn àròsô ôlörõ geere)ÀKÓÓNÚ IŚË
a. Ibùdó àti ahunpõ ìtàn
b. Àśà tó súyô
d. Àwôn kókó õrõ tó súyô
e. Êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá
ç. Ônà èdè àti ìsôwölo-èdè
7ÀŚÀ: Eré ÌdárayáÀKÓÓNÚ IŚË
a. ìtumõ eré ìdárayá
b. Oríśiríśi eré ìdárayá
i. Eré òśùpá bí i – bojúbojú, ta ló wà nínú
ôgbà náà abbl
ii. Eré ojoojúmö – àlö pípa, òkòtó, àrìn
títa, ayò títa
8ÈDÈ: ÒýkàÀKÓÓNÚ IŚË
a. kíka irínwó – êëdëgbêta ní èdè
Yorùbá: bí àpççrç; okòólénírínwó – 420
ojìlénírinwó – 440
õtàlénírínwó – 460
õrìnlénírínwó – 480 abbl
b. Kíka òýkà àárin wôn. Bí àpççrç:
oókanlénírínwó – 401
èjìlénírínwó – 402 abb
9LÍTÍRÈŚÕ: Àśàyàn Ìwé EwìÀKÓÓNÚ IŚË
a. Ewì kíkà
b. Kókó õrõ ajçmö-õrõ-tó-ń-lô láwùjô/ lágbàáyé.
– Ìśêföfábo
– ipò obìnrin
– ètò ôrõ-ajé
– ìkôlura êsìn/ àśà
– ìkóra-çni-ní-ìjánu nínú ìgbésí ayé õdö
d. Ônà èdè àti ìsôwölo-èdè
10ÈDÈ: Ìró Èdè YorùbáÀKÓÓNÚ IŚË
a. Àpèjúwe ìró köńsónáýtì
b. Àpèjúwe ìró fáwëlì
d. Àtç fáwëlì àti köńsónáýtì
11ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ 
12ÌDÁNWÒ 

 

JSS3 Third Term Scheme of Work for Yoruba

 TermThird Term
WeekTopicBreakdown
1ÒWE ÀTI ÀKÀNLÒ ÈDÈ KÉÈKÈÈKÉÀKÓÓNÚ
1. Ìtumõ òwe
2. Àbùdá òwe
3. ìwúlò òwe: fún àlàyé, ìkìlõ, ìmõràn, ìbáwí abbl
4. Àkànlò èdè – ìtumõ
5. Oríśi àkànlò èdè pêlú àpççrç
2ÈDÈ: Òýkà YorùbáÀKÓÓNÚ IŚË
1. Àtúnyêwò òýkà láti oókan dé êëdëgbêta (1-500)
2. ka òýkà láti oókan dé êëdëgbêta
3. Da fígõ àwôn òýkà náà mõ.
3ÀŚÀ: Ìtàn Ìśêdálê YorùbáÀKÓÓNÚ IŚË
1. Ìtêsíwájú ìtàn ìśêdálê Yorùbá
2. Àwôn ômô Õkànbí
3. Àwôn ôba ilê Yorùbá àti orúkô oyè wôn
4. Êyà Yorùbá àti êka èdè wôn
4LÍTÍRÈŚÕ: Àśàyàn ìwé àyôkàÀKÓÓNÚ IŚË
1. Àtúnyêwò àwôn àśàyàn ìwé ìtàn àròsô ôlörõ geere, ewì àti eréonítàn
2.ìtàn inú ìwé ní sókí
3.Êdá ìtàn
4.Ìfìwàwêdá
5.ibùdó ìtàn
6.Àhunpõ ìtàn
7. kókó õrõ tó jçyô
5ÈDÈ: Ìsõrí õrõÀKÓÓNÚ IŚË
1. Ìtêsíwájú lórí ìsõrí õrõ
2. Dárúkô àwôn ìsõrí õrõ Yorùbá: õrõ-orúkô, õrõ-àpönlé, õrõ-aröpò orúkô, õrõ-ìśe, õrõ-àpèjúwe, õrõ-atökùn, õrõ-àsopõ
3. Àlàyé kíkún lórí ipò àti iśë wôn nínú gbólóhùn
6FÓNËTÍÌKÌ: Ìró Èdè YorùbáÀKÓÓNÚ IŚË
1. Dárúkô àwôn ìró köńsónáýtì àti fáwëlì
2. Oríśi fáwëlì tí ó wà 3. Àpèjúwe ìró köńsónáýtì àti fáwëlì
4. Àtç köńsónáýtì àti fáwëlì
7ÀŚÀ: ÌsômôlórúkôÀKÓÓNÚ IŚË
Ìtêsíwájú lórí:
1. Àśà Ìsômôlórúkô
2. Àwôn ohun èlò ìsômôlórúkô
3.oríśi orúkô: orúkô àbísô, àmútõrunwá, àbíkú, oríkì, ìdílé ìnagijç abbl
8ÈDÈ: Akókò, ìgbà àti ojú ôjöÀKÓÓNÚ IŚË
Ìtêsíwájú nípa:
1. Sísô àwôn àkókò tó wà nínú ôjö
2. Sísô iye agogo tó lù
3. Ìlò a.m àti p.m ní èdè Yorùbá. Bí àpççrç, Aago méje àárõ, aago kan õsán, aago méje alë abbl
9ÈDÈ: Õrõ ÀyálòÀKÓÓNÚ IŚË
1. Oríkì õrõ àyálò
2. Õnà tí õrõ àyálò gbà wônú èdè Yorùbá. Àpççrç; êsìn, ôrõ-ajé, òśèlú, õlàjú abbl.
3. Àwôn èdè tí Yorùbá ti yá õrõ lò bí i èdè Gêësì, Haúsá, Hébérù, Lárúbáwá
4. Oríśi õrõ àyálò pêlú àpççrç.
10ÀŚÀ: ÌkíniÀKÓÓNÚ IŚË
Ìtêsíwájú nípa
1. Ìkíni ní onírúurú ìgbà àti àkókò
2. Ìkíni fún onírúurú ayçyç
3. Ìkíni fún onírúurú iśë
4. Ìkíni fún çni tí õfõ sê abbl
5. Ìśesí ní àsìkò ìkíni
11ÈDÈ: Êrô Ayára-bí-àśá (Computer)ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Àlàyé lórí èrò kõýpútà
2. Oríśi kõýpútà
3. Êyà ara kõýpútà
4. Ìwúlò kõýpútà
12ÀTÚNYÊWÒ IŚË ÌDÁNWÒ 
13ÌDÁNWÒ 

Recommended Yoruba Textbooks for Junior Secondary School 3

The recommended textbooks for Yoruba in J.S.S.3 include:

Textbooks (JS1 -3) 

  • Eko Ede Yoruba Titu Iwe Kininni (JS1) by Oyebamiji Mustapha et al 
  • Eko Ede Yoruba Titun Iwe keji (JS2) by Oyebamiji Mustapha et al 
  • Litereso atI Asa Yoruba JS3 by Mobolaji Arowosegbe 

Litereso Texts 

  1. Sisi Oloja by Olajumoke Bamiteko 
  2. Subu Sere by Lasunkanmi Tela 
  3. Olu Omo by D. O. Adisa 
  4. Atiteebi by Diipo Gbenro 
  5. Ijinle Arofa Yoruba  by Meedogbon Kola Ajiboye 

 

Text Book 

Eko Ede Yoruba Titun Iwe keta (JSS3) 

Litereso ati Asa Yoruba 

Mobolaji Arowosegbe

All JSS3 Scheme of Work

JSS3 Agricultural Science
JSS3 Basic Science
JSS3 Basic Technology
JSS3 Business Studies
JSS3 Christian Religious Studies
JSS3 Civic Education
JSS3 Computer Studies
JSS3 Cultural & Creative Art
JSS3 English Studies
JSS3 History
JSS3 Home Economics
JSS3 Islamic Religious Studies
JSS3 Literature
JSS3 Mathematics
JSS3 Hausa
JSS3 Yoruba

Download JSS3 Yoruba Scheme of Work

jss3-yoruba

Know what’s expected of you as an educator

Download the Unified Scheme of Work for JSS3 Yoruba

Professional Certification

CIBN Syllabus

CITN Syllabus

APCON Syllabus

Company

Career

Media Kit

SyllabusNG

© 2024 Created with Page 5 Digital
Download Syllabus