SS2 Yoruba Scheme of Work

Download the Senior Secondary School 2 (SS2) Unified Scheme of Work for Yoruba  to serve as a guide for educators

Home » SSS2 Scheme of Work » SSS2 Yoruba Scheme of Work

About SS2 Yoruba Scheme of Work

Yoruba is a language with profound historical importance, spoken by over 20 million people mainly in southwestern Nigeria, and extending into countries like Benin and Togo. It has a rich literary tradition, with early written works from the 19th century, including religious texts translated by missionaries. Yoruba serves not only as a means of communication but also as a vessel for cultural expression, embodying the traditions, values, and wisdom of the Yoruba people.

Studying Yoruba in SS2 using the Lagos State Unified Scheme of Work offers students a comprehensive understanding of the Yoruba language, literature, and culture. This curriculum is designed to meet national educational standards, fostering proficiency in speaking, reading, and writing Yoruba. Through a structured approach, students explore the rich heritage, traditions, and values of the Yoruba people, preparing them for higher education and promoting cultural appreciation and preservation.

Achievement Standards

Leyin gbogbo idaniekpo lon ede asa ati litreso ede Yoruba awn akekpo ti le;

Lo ogbon arojinle oun yoyanju lati salaye anipa ankoo faweli oro ayalo, gbolohun, apola abbi;

Npase ogbon aumose ati ibanisoro lati jiroro nipa eto oselu nile Yoruba, igbabgo Yoruba nipa oso ati aje;

Se amuo ogbon arojinle ati yiyanu isoro lati salaye awon eko ajemo-awujo;

Se atotonu nipa litreso alohun ati apileko ni ibamu si awon eko abala naa ninu eyi ti a ti ri asa, ihun, eko, ilo-ede;

Lo eko imo ero ayelujara la se ofintoto awon imo ode-oni;

Se omikinwin alaye nipa iwe litreso to Ajo WAEC/NECO.

Assessment Guide

Assessment methods in Yoruba are diverse, including written tests and oral exams. These evaluations measure not only students’ language proficiency but also their grasp of cultural content and their ability to use the language in real-life situations.

Communication skills are developed through both written and oral exercises. Students participate in reading comprehension tasks, analyzing short texts and answering questions to show their understanding. Writing exercises focus on constructing sentences, developing paragraphs, and basic composition, allowing students to express their thoughts clearly in written Yoruba.

Grading is based on a scale from A to F, with A signifying excellent performance, typically scoring around 70% or 80%, and F indicating failure, generally below 50% or 45%.

Download SSS2 Yoruba Scheme of Work

ss2-yoruba-scheme-of-work

Know what’s expected of you as an educator

Download the Lagos State Unified Scheme of Work for Senior Secondary School Two (SSS2) Yoruba.

SS2 First Term Scheme of Work for Yoruba

LAGOS STATE MINISTRY OF EDUCATION UNIFIED SCHEMES
OF WORK FOR SENIOR SECONDARY SCHOOLS
Yoruba Scheme of Work for Senior Secondary Schools 2(SSS2)
 CLASSS.S.S 2
 SUBJECTYoruba
 TERMFirst Term
WEEKTOPICSLearning Objectives
1Idanwo ranpe kinni ka’abo fun
awon akekoo
Laati ta awon akeeko yi lati pe okan won pada
si ile eko
EdeGbolohun eleyo oro-ise
i. Oriki ihun gbolohun eleyo
oro-ise
ii. Apola oruko ati apola ise
iii. Gbolohun akiyesi aletenumo
iv. oriki ati bi a se n seda
gbolohun akiyesi alatenumo
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le
1. da gbolohun eleyo oro ise mo ati ihun re
2. salaye ajosepo to wa laarin apola oruko ati
apoola ise
3. mo abuda gbolohun akiyesi alatenumo
4. dahun ibeere lori eko yi
AsaItesiwaju lori eko ile
-Eko imototo itoju ara ikinni,
oro siso, ounje sise, awo fifo,
ibowofagba, asepo ere pelu awon
egbe ati iro ojuse omo ninu
idagbasoke ilu ati awujo laapapo
gbigbe asa laruge
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le
1. salaye ohun to eko ile pinsi
2. mo orisirisi ona ti eko ile pinsi
3. so bi n se lorisirisi igba ati fun awon ise
abinbi Yoruba
4. mo ojuse won ninu idagbasoke ilu
5. dahun ibeere lori eko yii
LitItunpale asayan iwe literase ti
WAEC/NECO yan itan nipa
onkowe itan inu iwe ni soki eko
inu itan
 
2EdeAnko ati ijeyopo faweli ninu ede
Yoruba
1. kinni anko ati ijayepo faweli
ninu ede Yoruba
2. bawo lawon faweli se n ba ara
won jeyo po?
3. nje gbogbo fawelli lo le bara
won jeyo po?
4. akojopo ilana ti awon faweli
n’gba jeyo po
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le
1. so ohun ti ijeyopo/anko faweli je ninu ede
yoruba
2. mo bi awon faweli se ri ba ara won jeyopo
3. salaye awon faweli ti ko jeyopo ati lati
dahun ibeere lori eko yi
AsaIpa ti agbara aje n ko ninu ise
isegun ati iwosan
i. ipa ti aje n ko lati u iwosan ba
eniyan
ii. bi won ti le padigina iwosan ati
alaafia awon eniyan
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. se ekunrere alaye lori tani aje ati oso?
2. so iwulo aje ati oso ninu iwosan
3. da awon aje ati oso mo ati ona ti a le fi
bawon lo
4. nimo nipa ona ti won le gba mu eniyan
darapomo egbe won
5. dahun ibeere lori eko yii
LitItupale asayan iwe literaso ti Ajo
WAEC/NECO yan
-Moremi Ajasoro(prose) lati owo
Debo Awe
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le
1. ka iwe na ni akagbadun
2. soro nipa awon edaitan kookan
3. daruko ibudo itan
3EdeOro ayalo: ohun ti oro ayalo je
i. Ohun to n fa yiya oro lati inu e
de kan si ede miiran (Hausa,
Fulani, Larubawa ati Gessi)
ii. Ona ti a n gba ya oro lati inu
ede miiran afetiya ati ifojuwa
iii. Ayipada to ba batani iro ede
elede ti a ya wo inu ede Yoruba
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. Fun oro iyalo ni oriki
2. so inu awon ede ti a n ti ya oro wonu ede wa
3. da awon ona ti a gbaya oro mo
4. salaye iyipada to maan ba oro ti a ya wonu
ede Yoruba
4EdeGbolohun ede YorubaNi opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le
1. da orisirisi gbolohun ti owa mo
2. salaye orisirisi okookan awon gbolohun yi
3. salaye iyato laarin awon gbolohun na
4. dahun ibeere lori eko yi
AsaEre idaraya
i. Ere idaraya lati atijo
ii. awon ere ojumomo ati ere
osupa
iii. Ere atijo ati ere ita gbangba
abii
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le
1. salaye ohun ti ere idaraya je
2. soro nipa orisi ere idaraya ti o wa
3. mo bi a n fi se okookan ere idaraya
4. so iwulo awon ere wonyi
5. so iyato laarin ere idaraya ode atijo
LitSise itupale asayan iwe literaso ti
Ajo WAEC/NECO yan
-Ilo ede ati akanlo ede
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le
1. se itunpanle itan aroso moremi
2. daruko olu eda itan ati sise afihan bi o se
lagbara to
3. salaye bi onkowe se lo ede ati akanlo ede
4. dahun ibeere lori itan
5EdeAkaye ojoro-geere
-Sise ise po pelu awon akeeko
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le
1. daruko orisirisi akaye to wa
2. soro nipa b n se ka akaye akagbadun
3. wa itumo si awon oro to farahan
4. salaye eko to wa ninu re
5. dahun ibeere lori eko
AsaEre idaraya
i. Awon ere idaraya ti ode oni
ii. Lilo oro igbalode fun sise ere
idaraya
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le
1. da ere idaraya ode-oni mo
2. salaye bi n se n se awon ere wonyi
3. soyaato laarin ere idarayo aye atijo ati ode
oni
4. dahun ibeere lori eko yi
LitKika iwe ti ijoba yan fun idanwo
WAEC/NECO
-Moremi Ajasoro(prose) lati owo
Debo Awe
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le
1. tesiwaju ninu kika iwe naa
2. fa koko inu itan naa yo
3. dahun ibeere lori iwe naa
6EdeAkaye Ewi
i. Sise ise ninu yara ikawe lori
akaye elewi
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le
1. so yaato laarin akaye elewi ati ojoro geere
2. salaye abuda akaye elewi
3. fa koko inu ewi naa yo ati awon ona-ede
AsaEre idararaya!!!
i. Iwulo ati anfaani ere idaraya
ii. Aleebu ere idaraya
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le
1. ko nipabi a ti n se ere idaraya orisirisi
2. salaye ofin to de ere kookan
3. dahun ibeere to jemo eko naa
LitKika iwe litereso ti Ajo
WAEC/NECO yan
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le
1. so itan naa no soki
2. salaye koko ti itan naa da le lori
3. jiroro nipa eda itan kookan
4. dahun ibeere lori awon koko itan naa
7Idanwo ranpe/ Isinmi Idakeji saa
8EdeIhun oro
i. iseda oro
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le
1. mo awon ona miiran ti n gbe seda oro oruko
2. salaye bi n se lo atumo aarin lati seda oro
oruko
3. lo ilana apetumo lati seda oro oruko
4. da awon oro ti a seda nipa ilo isunki odidi
gbolohun mo
AsaEto iselu abinbi(II)
i. eto oye jije, oye idile, oye
ifinanilola, oye esin, oye ogboni,
oye ologun
ii. Ojuse awon oloye wonyi ninu
eto iselu
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. salaye bi n se oselu abinbi laye atijo
2. so iyaato laarin oye idile ati oye idiniola
3. so nipa ilana oye jije
4. bi a se n joye esin ogboni ati awon oye
miiran
LitKika iwe ti ijoba yan fun idanwo
WAEC/NECO
-Moremi Ajasoro(prose) lati owo
Debo Awe
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. tesiwaju ninu kika itan na
2. daruko olu-eda itan
3. so koko ti itan da le
4. jiroro nipa ogbon isotan to onkowe lo
9Edei. Oro iyalo
ii. awon ohun to se okunfa oro
iyalo
iii. ilana ti ari gba ya oro wonu
ede Yoruba
iv. Ofin to ro mo oro ayalo ninu
ede Yoruba
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. fun oro iyalo ni oriki ati apeere
2. bawo la se n ya oro wo inu ede Yoruba
3. da awon ohun to sokunfa yiya oro mo
4. salaye ifaramole ti awon oro ti ya wonu ede
Yoruba gbodo sewa
5. dahun ibeere lori eko
AsaIpolowo oja nile Yoruba laye atijo
i. idi ti n fi polowo oja
ii. awon oja ti a n polowo ati ona
a n gba polowo okookan won
Bi apeere-Agbado sise-Langbe
lori ebe abbi
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. So bi n se polowo oja ni orisirisi ona
2. salaye idi ti a fi n polowo oja laye atijo ode
oni
3. Da anfaani to
LitKika iwe ti ijoba yan
moremi Ajasoro
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. da iwe na ka ni akagbadun
2. fa koko inu iwe naa yo
3. ni oye lori ona lati kowe lojo iwaju
4. dahun ibeere lori eko yii
10EdeAnkoo ati ijeyewo faweeli
i. Awon fawelli to le bara won
jeyopo ati awon ti ko le ba ra won
jo yepo
ii. Yiya ate anko faweeli
iii. Alaye ofin to ro mo ijeyopo
faweeli
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. mo awon faweeli tole je yo po
2. salaye awon fawalli to le sise gege bi fawelli
akoko
3. da awon fawelli ti kole je ati idi ti ofi re n be
4. dahun ibeere to yejo
AsaIpolowo oja lode oni(II)
Awon ona ti n gba polowo oja
lode oni bi: ipolowo lori redio,
telefisan, iwe iroyin, ile iwe ipate
abbi
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. salaye awon ona ti n gba se ipolowo oja ni
ode oni
2. da awon iyato to ti de ba ona ipolowo oja
laye atijo
3. so anfaani to wa ninu ipolowo oja
LitIwe kika ti ijoba yan
Moremi Ajesoro-Debo Awe
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. so itan naa lekurere
2. mo ise ti onkowe n ran si awujo
3. fa koko inu itan naa yo
4. da awon ona ede/iwa ede inu itan naa mo
ki a si le lo ninu iso won
5. dahun awon ibeere lori eko yii
11Atunyewo lori gbogbo ise saa yi
lori ede, asa ati literaso yoruba

Oluko yo maa beere ibeere lori
akori ise kookan titi ti yo fi
kesejan
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. dahun ibeere lori gbogbo eko aleyinwa
2. mo bi ibeere yoo se jade ninu idanwo
3. da ilana ti a le tele lati dahun ibeere bo ti ye
4. ni anfaani lati beere ohun ti ko ye won lori
awon idanileko wonyi
12IDANWO IPARI SAA YIIIDANWO IPARI SAA YII

SS2 Second Term Scheme of Work for Yoruba

 CLASSS.S.S. 2
 SUBJECTYoruba
 TERMSecond Term
WEEKTOPICSLearning Objectives
1Idanwo ranpe ikini ka abo fun
awon akekoo
Lati ta awon akeeko ji lati pe okan wan pada si
ile-eko
EdeGbolohun eleyo oro-ise
i. onko ihun gbolohun eleyo
oro-ise
ii. Apola oruko ati apola ise
iii. Gbolohun akiyesi alatenumo
iv. oriki ati bi n se seda gbolohun
akiyesi alatenumo
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. da gbolohun eleyo oro-ise mo ati ihun re
2. salaye ajosepo to wa laarin apola oruko ati
apola ise
3. ma abuda gbolohun akiyesi alatenumo
4. dahun ibeere lori eko yi
AsaItesiwaju lori eko ile
-Eko imototo, itoju ara, ikini,
oro siso, awo fifo, ibowofagba,
asepo ere pelu, awon egbe ati iro
ojuse omo ninu idagbasoke ilu ati
awujo laapapo gbigbe asa laruge
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. salaye ohun ti eko ile pinsi
2. mo orisirisi ona ti eko ile pinsi
3. so bi n tun ile se kini lorisirisi igba ati fun
awon ise abinbi Yoruba
4. mo ojuse won ninu idagbasoke ilu
5. dahun ibeere lori eko yi
LitItupanle asayan iwe literaso ati
Ajo WAEC/NECO yan
Itan nipa onkowe, itan inu iwe ni
soki eko inu itan
 
2EdeAnkoo ati ijeyopo faweli ninu ede
Yoruba
i. Bawo lawon faweli lo le bara
won jeyo po
ii. Nje gbogbo faweli lole bara
won jeyo po
iii. akojopo ilana ti awon faweli
n’gba jeyo po
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. so ohun ti ijeyopo/ankoo fawelli je ninu ede
Yoruba
2. mo bi awon faweli se ri ba won jeyopo
3. salaye awon faweli ti ko jeyopo ati lati
dahun ibeere lori eko yii
AsaIpa ati agbara aje n ko ninu ise
isegun ati iwosan
i. Ipa ati aje n ko lati u iwosan ba
eniyan
ii. Bi won ti le pagidina iwosan
ati alaafia awon eniyan
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. se ekunrere alaye lori tani aje ati oso
2. se iwulo ati oso mo ati ona ti ale fi won lo
3. nimo ni pa ona ti won le gba mu eniyan
darapomo egbe won
4. dahun ibeere lori eko yii
LitItunpale Asanya iwe literaso ti
Ajo WAEC/NECO yan
-Moremi Ajasoro(prose) lati owo
Debo Awe
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. ka iwe naa ni akagbadun
2. soro nipa awon eda itan kookan
3. dahun ibudo itan
3EdeOro Ayalo: Ohun ti oro ayalo je
i. ohu to n fa yiya oro lati inu ede
kan si ede miiran
ii. Ona ti a n gba ya oro lati inu
ede miiran Afetiya ati Afojuya
iii. Ayipada to ba batani iro ede
elede ti a ya wo inu ede Yoruba
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. fun oro iyalo ni oriki
2. so inu awon ede ti a a ti ya oro wonu ede wa
3. da awon ona ti a gbaya oro omo
4. salaye iyipada to maa n ba oro ti a ya wonu
ede Yoruba
AsaEto ogu pinpin I
i. Itumo ogun ati ohu ti afin je
ogun
ii. Iyato laarin ofun iya ati baba
iii. ona ti a n gba pin ogun ni ile
Yoruba
iv. Aeon to ni eto si ogun jije
v. Aleeto to ro mo ogu pinpin
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. salaye eto ogun pinpin nile Yoruba
2. da awon ona ti Yoruba n gba pin ogun
3. so iyato laarin ogun uya ati baba
4. mo awon to ni eto si ogun mo
5. so wahala to n maa n wa leyin ogun pinpin
6. dahun ibeere lori eko yi
LitSise itunpale asayan iwe litereso
i. ona ilo ede ni akanle ede owe
ii. Sise onkiniwin wan
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. so bi onkowe se lo awon ona ede/ewa, ede bi
owe, akanlo ede, awitunwi afiwe ati bee bee lo
boya owa ni ibamu
2. mo bi a se le lo orisirisi awon ana ede wonyi
ninu iso wa
4EdeAroko: Leta aigbabefe
i. Igbese leta aigbabefe
ii. Adereesi, deeta, ikini, Akole
koko, oro, ikaadi, oruko ati
ifomosi
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. so nipa leta aigbabefe
2. so ilana ti an tele lati ko leta aigbabefe
3. salaye abuda leta aigbefe
4. da iyato mo laarin leta gbefe ati aigbefe
5. dahun ibeere lori eko yi
AsaEto Ogun pinpin(II)
Ipa ti ijoba n ko lori ogun pinpin
laye ode oni
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. se afiwe ilana ogun pinpin laye atijo ati ode
oni
2. mo ipa ti ijoba ko lori ogun pinpin
3. so ewo lo daraju ninu awon ilana yii
4. dahun ibeere lori eko yi
LitSise itunpale asayan iwe litereso
i. ona ilo ede ni akanle ede owe
ii. Sise onkiniwin wan
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. so bi onkowe se lo awon ona ede/ewa, ede bi
owe, akanlo ede, awitunwi afiwe ati bee bee lo
boya owa ni ibamu
2. mo bi a se le lo orisirisi awon ana ede wonyi
ninu iso wa
5EdeEde iparoye tabi isunki
i. kinni iparoye/isuki?
ii. inu ihun ti ipaye ti le waye
a. Apola oruko
b. Awon ihun miiran
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. salaye kinni iparoye/isunke
2. daruko awon ihun ti iparonye/isunki ti le
waye
3. mo awon iro ti a n paje ninu awon ihun
wonyi
4. so idi ti iparoye/isuki se waye ninu ede
Yoruba
5. dahun ibeere lori eko yi
AsaEti idajo laye atijo
i. Ona ti an fi se idajo laye atijo
beere lati odo oba baale ati ijoye
ii. Ipa ti emese kan ninu eto idajo
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. so be a n se se eto idajo laye atijo
2. mo ipa ti obe ijoye ati baale ko ninu eto
idajo sise
3. salaye pataki emese gba ati laarin oba nko
ninu eto idajo
4. dahun ibeere lori eko
LitLiterature kika: Iwe ti ajo WAEC
ati NECO yan
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. ka ewi ninu iwe na akadato/akagbadun
2. mo nipa onkowe to ko ewi na
3. daruko awon akole ewi inu iwe na
4. fa koko inu awon ewi wonyi yoo
5. dahun ibeere lori eko na
6EdeAranmo
i. Itumo aranmo
ii. Orisirisi Aranmo
iii. Ofin to de aranmo
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. Fun aranmo ni oriki
2. so orisirisi aranmo to wa
3. salaye bi iro se, ra mo aranmo
4. da iro afaranmo mo yato si iro agbaranmo
5. salaye arnmo iwaju ati aranmo eyin
6. dahun ibeere lori eko yi
AsaEto idajo
i. Idajo ni ode oni ni ile ejo
ii. orisirisi ile ejo: ile ejo ibile, ile
ejo giga, ile ejo kolemilorun, ile
ejo toga julo
iii. igbimo eleti gbaroye ati bee
bee lo
iv. ipa ti olopa ati woda n ko ninu
idajo ode oni
v. ise agbejoro ninu idajo ode oni
vi. eto yiyanju aawo lori redio ati
telefisan
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. salaye eto idajo laye ode oni
2. da orisirisi ile ojo to wa
3. so boya awon igba si fun inu ninu efo idajo
ode oni
4. mo ipa ti olopa ati woda n ko ninu eto idajo
ode oni
5. bo koko ise igbajumo ninu eto idajo ode oni
6. salaye pataki/iwulo awon eto ori telefisan ati
redio lori eto idajo ode oni
LitLiterature kika: Iwe ti ajo WAEC
ati NECO yan
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. ka ewi ninu iwe na akadato/akagbadun
2. mo nipa onkowe to ko ewi na
3. daruko awon akole ewi inu iwe na
4. fa koko inu awon ewi wonyi yoo
5. dahun ibeere lori eko na
7Abewo awon obi si ile ile eko lati
wo ise awon omo wan
 
8EdeEde oro agbaso
i. Afo asafo (oro enu oloro)
ii. Afo agbaran (oro agabso)
iii. Awon wure ti a maa n lo ninu
oro agbaso
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. so kinni oro agbaso
2. salaye aso asafo ati afo agbaran
3. da awon wuren ti a n lo ninu afo agabran
4. mo ilana ti a le tele lati se agbaran
5. dahun ibeere lori eko yi
AsaAroko pipa
i. Orisirisi awon n kan ti a fi n
paroko ati itumo won
ii. idi/anfaani ti n fi pa aroko ni
ile Yoruba
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. sekurere alaye lori ohun to n je aroko pipa
2. da awon ami aroko mo ati ohun ti won duro
fun
3. mo awon ohun to le ba aroko je
4. so tito ati aito aroko pipa
5. iyipada wo ni olaju ti mu ba aroko pipa
6. dahun ibeere lori eko na
LitKika iwe literaso Yoruba ti ijoba
yan : oro enu akawi lati owo
Ayomide Akanji
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. da ewi naa ka
2. salaye koko ti ewi naa dale
3. fa ona ede inu awon ewi na
4. mo ilana ati ohun ti a n fi kewi mo
5. dahun ibeere lori eko wonyi
9EdeOro/gbolohun onippona
i. Itumo ponna
ii. Akipojo awon oro onipoona
iii. Alaye lori itumo oro ati
gbolohun onipoona
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. fun oro/gbolohun poona ni oriki/itumo
2. se akojopo awon oro ati gbolohun poona
3. wa itumo ti a le ri ninu oro awon poona ati
gbolohun poona wonyi
4. dahun ibeere lori eko yii
AsaEewo ni ile Yoruba
i. Ki ni eewo?
ii. orisirisi eewo ati itumo won
iii. Ki ni o maa sele ti eniyan ba
deja eewo ati atubotan re
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. salaye eewo melo lo wa
2. kini eewo wa fun?
3. daruko ohun ti a n lo eewo fun
4. ki ni o maa sele si eni toba deja
5. dahun ibeere lori eko yii
LitKika iwe literaso Yoruba ti ijoba
yan : oro enu akawi
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. da ewi naa ka
2. salaye koko ti ewi naa dale
3. fa ona ede inu awon ewi na
4. mo ilana ati ohun ti a n fi kewi mo
5. dahun ibeere lori eko wonyi
10EdeAwon gbolohun ede Yoruba
i. Oriki ati alaye kikun lori awe
gbolohun
ii. Orisi awe gbolohun
iii. Olori awe gbolohun
iv. Awe gbolohun afarahe
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. so hun ti awe gbolohun je ni ede Yoruba
2. Mo orisi awe gbolohun ti wa ninu ede
Yoruba
3. Da olori awe gbolohun mo yato si afarahe
4. dahun ibeere lori eko
AsaIgbagbo ati ero Yoruba nipa
Ajinde leyin iku
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. so nipa igbagbo ati ero awon TYoruba nipa
ajinde
2. salaye awon nkan to fi ese igbagbo wonyi
mule
3. dahun ibeere lori eko
LitAwon eka ede Yoruba
i. Ohun ti eka ede je
ii. Awon eka ede to wa ni ipinle
kookan
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. Salaye kini eka ede
2. daruko eka ede to wa ni agbegbe tabi ipinle
kookan
3. da iyato to wa laarin awon eka ede wonyi mo
4. mo ohun to sokufa iyato wonyi
5. dahun ibeere lori eko
11EdeApola ninu gbolohun ede Yoruba
i. Apola oruko
ii. Apola ise
iii. Ihun apola
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. se ekunrere alaye lori Apola gbolohun ede
Yoruba
AsaIgbagbo Yoruba nipa olodumare
i. Tani Eledumare?
ii. Awon oruko to Yoruba fin pe
Olodumare
iii. Abuda ti awon Yoruba fin pe
Olodumare
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. So tani Olodumare
2. mo be tito Olorun se to
3. wa awon oruko ti n Yoruba pe olorun to fi
tito re han Aterekaye
4. mo pataki Olodumare laarin awon ede
LitKika iwe ti Ijoba yanNi opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. Salaye awon ewi inu iwe na
2. so koko to jeyo ninu okookan awon ewi na
3. mo ona isowo lo ede akewi na
4. dahun ibeere lori awon ewi naa
12Atunyewo eko lori gbogbo ise saa
yi
Akekoo yoo le gbaradi fun idanwo
-Se atunse nibi to ba ri pe ko ye oun to
-Mo bi a se le dahun ibeere
 Idanwo Pari SaaIdanwo Pari Saa

SS2 Third Term Scheme of Work for Yoruba

 CLASSS.S.S 2
 SUBJECTYoruba
 TERMThird Term
WEEKTOPICSLearning Objectives
1Idanwo ranpe ikinni kaaboLati je ki awon akeeko mo pe ise ti beere
EdeAtunyewo eko lori aroko ajemo
isipaya
i. Ilana agbekale aroko ajemo
isipaya
ii. Akole ifaara koko oro
agbalo/agbagbo
iii. alaye kikun lori eto ipin afo
isowo lo ede
iv. kiko aroko lori awon akole kan
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. so ohun ti aroko ajemo isipaye je
2. se amuto eto ipin afo ti ona isowo lo ede da
ilana ti a n fi ko irufe aroko yii mo
3. mo pe ilana agbekale eya aroko kookan yato
si ara won
4. dahun ibeere lori koko idanilekoo
AsaAtunyewo eko lori eko ile
i. Kinni itoju ara ati ile ibbowo,
fagba, suuru, otito siso, iforiti
igboran ati iwa irele
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. so ohun ti eko ile je tabi dale
2. salaye oniruuru ona ti awon Yoruba n gba
lati ko omo ni eko ile
3. da bi a se n kinni ni orisirisi igba/akeeko
4. ma oriki fun orisirisi ise abinbin ati idahun
si won
5. mo bi ase n soro lawujo
6. se amulo awon ikini wonyi pelu idanhun si
okookan won
2Edeatunyewo eko lori silebu/ede
Yoruba
i. Kini silebu/oriki silebu
ii. Orisi silebu to wa
iii. Alaye lori ihun silebu kookan
iv. Alaye lori silebu alakaaro,
konsonanti ati fawelli
v. Pinpin oro si silebu
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. mo orisi ihun silebu to wa
2. da awon ihun silebu wonyi mo yato si ara
won
3. salaye awon ofin to de silebu awon Yoruba
4. pin oro si silebu
5. dahun oniruuru ibeere lori eko yii
AsaAtunyewo ise abinbi
i. Ise agbe
ii. Ise agbede
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. ni imo lori ise abinbi Yoruba
2. imo lori ona ti n gba se won
3. da ohun elo ise kookan mo
4. so iyipada to de ba awon ise abinbi wonyi
LitItesiwaju lori atupale awon iwe
litereso oro oru akewi
Ayomide Akanji
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. ohun ti an fi kewi
2. igbekale ewi pe ile si ila na
3. koko ti ewi kookan daale
4. fa ona/ede inu awon ewi wonji yo
3EdeAtunyewo aroko lori aroko
onisoro gbese
i. Alaye lori aroko onisoro gbese
ii. kiko aroko onisoro gbese to
dale isele awujo
iii.
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. salaye ohun ti aroko onisoro gbese je
2. so ilana/igbekale aroko yii
3. ko aroko lori orisirisi ori oro to je mo aroko
onisorogbese
AsaOna igbanosoro
i. lilo aworan eya ara fun
ibanisoro
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. se ekunrere alaye lori ona ibanisoro
2. so orisi ona ti a le gba fi bara eni soro lawujo
Yoruba
3. se amulo awon ona wonyi bi won ba soro
LitSise atupale sanyan iwe ti ijoba
yan Oro Enu Akewi lati owo
Ayomide Akanji
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
Bi a se n se atupale iwe ninu ede Yoruba Fa asa
yoruba to suyo ninu itan naa yo
4EdeAtunyewo ihun oro
i. Siseda oro oruko nippa lilo
afamo ibere aarin
ii. Afaye lori awon oro oruko ti o
ko seda sugbon ti won dabi eyi ti
aseda be ile
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. da iyato to wa laarin oro ti a seda ati eyi ti a
ko seda
2. salaye ona ti n gba seda oro ninu ede Yoruba
AsaItesiwaju eko lori ona ibanisoro
laye ode oni bii, telefisan, redio,
foonu, iwe iroyin, meeli ati fasi
(fax)
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. ona ibanisoro ode oni to wa
2. so iwulo won
3. bawo la se n lo won
LitSise atupale sanyan iwe ti ijoba
yan
i. Awon ilo ede/Akanlo ede
ii. Sise orikiniwin wan
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. fa koko to wa ninu awon iwe na yoo
2. samulo awon ijinle oro to suyo ninu iwe naa
3. wa itumo si awon oro tuntun ti won ba pade
5EdeOnkaa Yoruba lati egbaa de oke
medogbon(200-500,000)
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. ka onka Yoruba lati egba de medogbon
2. se amulo won ninu oro ati ise won
AsaAwon orisa ile Yoruba
i. Ogun, Obatala, Esu
ii. Awon ohun ti a n fi boowan ati
oriki okookan won
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. da awon orisa Yoruba wonyi mo
2. se lo nipa ojubo wan
3. so nipa awon olusi wan
4. mo oriki orisa kookan
5. salaye ibasepo to wa laarin awon orisa wonyi
LitKika asaye iwe ti ijoba yan
oro enu Akawi lati owo Ayomide
Akanji
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. ka iwe na ni akaaja gaara ati akagbadun
2. salaye ohun ti awon ewi na dale
3. ni imo lori bi a se n se agbekele ewi
6EdeOnka Yoruba lati oke medogbon
de aadota 500000-1000000
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. ka onka yi lati 500,000-1,000,000
2. le se aropo ati ayokuro ni onka Yoruba
AsaAwon orisa ile Yoruba ati bi a n
se bo won
i. Orunmila, Sango
ii. Awon ohun ti a n fi boowan ati
oriki okookan won
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. da awon orisa Yoruba wonyi mo
2. salaye tani orunmila ati sango
3. da awon oworo won mo
4. bawo lanse bo won
5. mo eewo won
LitKika asayan iwe ti Ajo
WAEC/NECO yan
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. ka iwe na ni akagbadun
2. fa koko inu itan na yo
3. dahun ibeere to ba suyo lori awon iwe naa
7Idanranwo ranpe /isinmi idaji
saa
Idanranwo ranpe /isinmi idaji
saa
8EdeAtunyewo awon eya aro ifo
i. Lilo awon eya ara ifo
ii. Alaye lori afipe asunsi ati afipe
akanmole
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. da awon eya ara ti an lo fun iro ede pipe mo
2. so wya ara ti a n lo lati iro kookan
3. salaye ati pe asunsi ati akanmole
4. so iyaato laarin afipe asunsi ati aknamole
AsaAwon orisa ile Yoruba ati bi a n
se bo won
i.Awon orisa miian ni agbegbe
awon akeeko
ii. Ipo orisa ni ile Yoruba
iii. Pataki awon orisa ni awujo
Yoruba
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. da awon orisa ile Yoruba mo
2. so itan orisi kookan
3. soro nipa bi n se n bowon
4. da awon olusin won mo
5. ipo orisa abi pataki orisa laarin Yoruba
6. dahun ibeere lori eko yii
LitKika asayan iwe ti Ajo
WAEC/NECO yan
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. ka iwe na ni akagbadun
2. fa koko inu itan na yo
3. dahun ibeere to ba suyo lori awon iwe naa
9EdeAtunyewo awon iro ninu ede
Yoruba
i. iro Fawelli
ii. iro konsonanti ati iro ihun
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. so iro meta to gbe ede Yoruba duro
2. salaye iwulo okookan won
3. da iye fawelli to wa mo
4. mo iye iro konsonanti awon to je ase silebu
5. dahun ibeere lori eko yi
AsaEro ati igbagbo awon Yoruba oso
ati aye
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. so nipa oso ati aye
2. salaye iru eda tabi eniyan ti wonje
3. mo bi a se le dawon mo
4. won yoo le so nipa agbara aye ati oso
LitKika iwe literaso ti ijoba yan
Oro Enu Akewi-Ayomide Akanji
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. so ilana ti a n gba tabi tele lati ko ewi
2. mo ohun ti a n fi kewi
3. da abuda ewi mo
4. fa awon ona ede inu awon ewi na yo ni
ibamu pelu bi n se lo won
10EdeAtunyewo eko lori ami ohun ati
iro konsonanti
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. so nipa ami ohun meteeta pelu ami won
2. fi ami si ori oro ati pataki ami ohun
3. le sapejuwe awon iro konsonanti leyo
kookan
4. dahun ibeere lori eko yii
AsaAsa ero ati igbagbo Yoruba lori
akudaya ati abami eda bi egbere
iwin, ebora, ati bee bee lo
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. so nipa akudaya ati abami eda
2. salaye boya iyato wa laarin akudaya ati
abami eda
3. so boya akudaya ati abami eda si tunwa laye
ode oni
4. kilo sokunfa ati ona abayo
LitKika iwe literaso ti ijoba yan
Oro Enu Akewi-Ayomide Akanji
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. ka ewi naa ni akagbadun
2. ronu jinle lati le ko ewi ti won naa
3. je ateegun fun akekoo to ba ni ebun ewi
4. da abuda ewi mo
11EdeAtunyewo eko lori ami ohun ati
iro konsonanti
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. so nipa ami ohun meteeta pelu ami won
2. fi ami si ori oro ati pataki ami ohun
3. le sapejuwe awon iro konsonanti leyo
kookan
4. dahun ibeere lori eko yii
AsaIgbagbo Yoruba nipa ori tabi
Eleda
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. so boya ori tabi eleda yato
2. salaye pataki ori eleda
3. so igbagbo Yoruba nipa ori
4. dahun ibeere lori eko yii
LitKika iwe literaso ti ijoba yan
Oro Enu akewi-lati owo Ayomide
Akanji
Ni opin idanilekoo yii awon akekoo yoo le:
1. ka ewi naa ni akagbadun
2. ronu jinle lati le ko ewi ti won naa
3. je ategun fun akekoo to ba ni ebun ewi
4. da abuda ewi mo
12Atunyewo eko lori awon ise saa
kini de iketa
Atunyewo eko lori awon ise saa
kini de iketa
13Idanwo pari saa keta lori ede, asa
ati literaso Yoruba
Idanwo pari saa keta lori ede, asa
ati literaso Yoruba
 Idanwo ipari saaIdanwo ipari saa

Recommended Yoruba Textbooks for Senior Secondary School 2

The recommended Yoruba textbooks for SSS2 include but are not limited to the following:

WAEC/NECO LITERATURE TEXTS YORUBA LITERATURE TEXTS (2021 – 2025)  

ORAL LITERATURE 

1 – DRAMA: Ege Dida by S.M. RAJI

Extension Publ. 

2 – AKOJOPO ALO IJAPA APA KIN-IN-NI by Adeboye Babalola

UP Plc.  

3 – POETRY: Awon Oriki Orile Metadinlogun by Adeboye Babalola    

Longman Nig. Plc      

WRITTEN LITERATURE    

Prose: Moremi Ajasoro by Debo Awe

Elyon Pub. Ilesa

Drama: Nitori Owo by Akinwumi Isola 

Sumob Pub. Osogbo  

Poetry: Oro Enu Akewi by Ayomide Akanji 

Genius Books Publications  

MAIN TEXTBOOKS    

I – Eko Ede Yoruba Titun SS1-3 by Oyebamiji Mus et al UPL Plc. Temaja Prints  

II – Litireso at Asa Yoruba by Mobolaji Arowosegbe 

Download SSS2 Yoruba Scheme of Work

ss2-yoruba-scheme-of-work

Know what’s expected of you as an educator

Download the Lagos State Unified Scheme of Work for Senior Secondary School Two (SSS2) Yoruba.

SyllabusNG

© 2024 Created with Page 5 Digital
Download Syllabus