Primary 3 Yoruba Scheme of Work

Download the Unified Basic 3 Scheme of Work for Yoruba to serve as a guide for educators and primary school teachers

Home » Primary 3 Scheme of Work » Primary 3 Yoruba Scheme of Work

About Yoruba Scheme of Work for Primary 3

The Yoruba scheme of work for primary 3 is a means by which the pupils will understand the basic Yoruba culture and traditions like responsibilities, proverbs, and traditional attire. 

The scheme of work for this academic session covers various topics such as responsibilities, proverbs, household items, proverbs, good behaviour, play plots, traditional taboos, heroes, wisdom and behavioural songs.

The educator should avoid using English to communicate with the pupils while teaching this subject. At the end of each class, the pupils should be able to answer questions based on the lesson.

Download Primary 3 Yoruba Scheme of Work

primary3-yoruba

Know what’s expected of you as an educator

Download the Lagos State Unified Scheme of Work for Primary 3 Yoruba

Primary 3 First Term Scheme of Work for Yoruba

LAGOS STATE GOVERNMENT MINISTRY OF EDUCATION UNIFIED SCHEMES
OF WORK FOR PRIMARY SCHOOLS
Yoruba Scheme of Work for Primary/Basic 3
 CLASSPrimary/Basic 3
 SUBJECTYoruba
 TERMFirst Term
WEEKTOPICSLearning Objectives
1Idånwo Ikini Kaäbö Si Saa KinniNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoöo le:
i. Dåhun ibere iwåju won
ii. Se ätunse ti o ye Iåti gbaradi fun isé Kinni.
2Agbéyéwö Ise Säa KojaNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoöo le:
i. Ye Awon ise odun keji wo Yékeyéké
ii. Dahun iberé abé åyéwö
3EdeOnkä ni édé Yoruba 61-100Ni Opin Idanilekoo, Akekoo yoöo le:
i. ka önkä låti ogota dé Ogorun-un
ii. Se idåmo äröpé ati åyokurö
iii. Dåhün lbééré abé eko
AsaOfin OpöponaNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoöo le:;
i. So ni päto ami öfin oju popo
ii. Sälåyé iwulö öfin oju popo
iii. Dahün ibééré abé éko
LitEwi AkénilégbonNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoöo le:;
i. Ka pélu ké ewi nåå
ii. Fa koko inu ewi nåä yo
iii. So åyorisi ewi nåä
iv. Dåhün lbééré abe eko
4EDEOjuse Obi si Omo
Ipésé ääbö inäwö
Ni Opin Idanilekoo, Akekoo yoöo le:;
i. Sålåyé ojuse obi si omo
ii. Dåruko bf i; méta ojuse obi si omo
iii. Lo öwe ti o bå åkori nåä mu
iv. Da’hün ibéére abe eko
Asalse Owo ati Ise onåNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoöo le:;
i. Dåroko orisii ise owo åti ise onä
ii. So bi a nse se ookokan won
iii. Dåhün ibééré abe éko
LitAlo ApaméNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoöo le:;
i. Pa ålo åpamo to moyan Iori
ii. Fa koko eko yo
iii. Dåhün åwon ibééré abé eko
5EdeSilébü
Ijébu__ I-je-bu
Oronibö__O-ro-ni-bo
Ni Opin Idanilekoo, Akekoo yoöo le:;
i. Pin Oro si silébü
ii. Lo åmi ohün fun pinpin silébü
iii. Dåhün ibééré abé eko nåå
AsaAwon ohun élö inu iléNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:;
i. Dåruko orisi ohun élö to ninu ilé
ii. So ise oköokan wan
iii. Dåhün ibééré abé eko nåå
Litltån Aroso
Ogboju Ode ati Omo Kinniun
Ni Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:;
i. So itan äroso nåå dåradåra
ii. Fa koko inu iwé itån nåå yo,
iii. Dåhun ibééré abé éko
6EdeOwe ni Ile YonibåNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Pa åwon owe ti o ni itumö
ii. Fa koko inu owe nåå yo
iii. Dåhün åwon ibééré abé éko
Asalwå rereNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:;
i. So ohun ti iwå rere pe fun
ii. So åbudå awon iwå rere
iii. Dahun ibééré abé eko
LitEré Onise Onä AbüjåNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. So akori eré sise na
ii. Dåruko åwon olukopa
iii. So atunbotan eré nåå
7Ägbéyewo Eko Isé Idaji Såå Kinni Lori
Edé,
Äsä
Litiréso
Ägbéyewo Eko Isé Idaji Såå Kinni Lori
Edé,
Äsä
Litiréso
8EdeOnka ni édé Yorübå 101-130Ni Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Ka onka ni äkäyé
ii. Ko onka nåå ni édé Yorübå
iii. Se idåmö. idi ati eyo
iv. Dåhün ibééré abé éko
AsaAwon ééwö ilé YorübåNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Dåruko åwon ééwo a ni
ii. So Ohun ti ééwo tumösi
iii. Dåhun ibééré abé éko
LitÄwon Akoni ilé YorubåNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Dårüko awon Akoni ni ilé Yorübå
ii. So ohun ti itumo akoni pe fun
iii. Dåhun ibééré abe eko
9EdeSipéli Oro
Owo
Aga
llekün
Aago
Odo
lbüsün
Ni Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Sipéli åwon oro ti oluko pe
ii. Se idåmo äwon oro nåå pélu åwörån
iii. Dåhün ibééré abé éko
AsaAgo wiwö ni ilé YorubaNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Daruko orisirisi aso aye ati jo
ii. So pate idi ti a fi to wo aso
iii. So ni soki awon asiko kookan
iv. Dahun ibere abe eko
LitOrin Akonilogbon ati Akomoniwa


Ni Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Ko orin akonilogbon ati akomoniwa
ii. Fa itumo yo ninu orin na
iii. KO bi a se n’ ko orin naa
iv. Se eré ti o ni itumö
10EdeAkanlö ede:
-terigbaso
-juba ehoro
-Okete boru
-na papa bora
-gbe aayan mi
Ni Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. So agbekuro akanlo édé
ii. se idåmo äti itumo åkanlo inu gbolohun
iii. Dahun ibere abe eko
AsaIpolowo Ojä ni öde-öni äti ayé åtijoNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. So bi a se n polowo oja tita
ii. Ménuba äwon ojä fun ip0lowo
iii. Sälåyé idi ti a fi polowo ojä tita
LitEwi Igbålodé
-Oluko
-Iwé mi
Ni Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Ka ewi Igbälodé
ii. Fa koko inu ewi naa yo
iii. Dahün ibéré abé eko na
11EdeOnkå ni édé Yorübå 131-150Ni Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Ka onka ni å kayé
ii. Ka äwon Figo nåå bi o tiye
iii. Se ldåmo idi åti eyo
iv. Dahün ibéré abé eko na

AsaIse TéloNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Ni oye ise Télö ni koko
ii. So Irufé Awon To Le ko ise Nåa
iii. Sälåyé isepåtäki ise owo
iv. Dåhün ibééré abé eko
LitItån ArosoNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. So itån äröso
ii. Fa koko inu iwé itån nåå yo
iii. Dåhün ibééré abé eko na
12EdeAgbéyewö éko Ise Idaji Såå Kinni Lori
-Edé
-Asa ati
-l.itireso
Agbéyewö éko Ise Idaji Såå Kinni Lori
-Edé
-Asa ati
-l.itireso
13 ldånwo Såå Kinni Iori édé, aså åti Literaso

Primary 3 Second Term Scheme of Work for Yoruba

   
 CLASSPrimary/Basic 3
 SUBJECTYoruba
 TERMSecond Term
WEEKTOPICSLearning Objectives
1Idanwô Ikini Kaâbo Si Sâa KetaNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Dåhün ibééré abé eko na
ii. Se atunse abe eko
2Agbeyewo ise saa kinniNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Ye awon eko saa kinni wo dada
ii. Dåhün ibééré abé eko na
3EdeSise NkanNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Gbe ohun to oluko ba ni ijo si
ii. So ohun ti ogbo leralera
iii. Se nkan to oluko ba ni kose
AsaItesiwaju IkinniNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. So bi a ti n’ kiri ni orisirisi akoko towa
ii. So pataki ikinni ni awujo ile Yoruba
iii. Dåhün ibééré abé eko na
LitOrin ere idarayaNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Ko ara won jo si abe igi orombo fun igbaradi
orin kiko
ii. jo si orin tin wan ko pelu atewo
iii. Dåhün ibééré abé eko na
4EdeSiso oro onileta poNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. So oro onileta meta po nipe titele itana F+K+F
ii. Ko oniruru apeere oro onileta mata jade
iii. Dåhün ibééré abé eko na
AsaOrisirisi eso ile waNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Daruko awon eso ile wa
ii. So pataki eso kookan
iii. Pin won si owoowo
iv. Dåhün ibééré abé eko na
LitAlo pipaNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Pa oniruuru alo npamo ati apagbe
ii. wa idahun si awon alo kookan tin won ba pa
iii. Dåhün ibééré abé eko na
5EdeIsorongbesi laarin Oluko ati akekooNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Beere ibere laarin oluko si akekoo
ii. Se ibeere laarin akekoo si oluko
iii. Dahun itakurosi to o waye laarin awon mejeeji
AsaOrin KikoNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Ko orin kan pato
ii. Fa koko inu orin na
iii. Gba laaye akekoo lati ko orin naa daadaa
iv. Dåhün ibééré abé eko na
LitEré OniseNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Se eré onise kékeré
ii. Sälåyé ohun ti eré nåä dä lé Iori
6EdeOnkå ni édé Yorübå 151-180
Ookånlélåådöje dé Ogésån-ån
Ni Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Ka önkä nåä yékéyéké
ii. Ko. åwon Figo nåå ni édé Yorübå
iii. Se idämö o lé äti d din fün åröpö äti äyokuro
AsaÄwon önå ibåraenisöröNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. So itumo ibåraenisoro
ii. Dåruko. åwon önå ti å n’ gbå ba éniyån soro
iii. Dåhün awon ibééré abé eko
Litltån ArösoNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Ka itån åröso nåä däradåra
ii. Fa koko inu itån nåå yo.
iii. Dahün åwon ibééré abé eko
7Ägbéyewo éko lse Idaji Såä Keji Léri
Edé
Äsä
Litiréso’
Ägbéyewo éko lse Idaji Såä Keji Léri
Edé
Äsä
Litiréso’
8EdeArépö OrukoNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. ki oriki aropo oruko
ii. Lo äwon öro nåä ni gb0lohün
iii. So wän ni ipö Olüwå åti åbö
AsaIse åjogunbå ilé YorübåNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Ménuba åwon ise äjogünbå ilé Yorüba
ii. So äwon ohun élo fun ise köokan
iii. Dåhün ibééré abé éko
LitAlo ApamoNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Pa ålo åpamo
ii. So itumo ålo nåä
iii. Dåhün ibééré abé eko
9EdeOweNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Pa öwe ti oni itumo
ii. Sälåyé owe nåå
iii. Dåhun ibééré abé eko
AsaIpolowo OjäNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Sälayé äwon ojä títa äti rírä ni ilu Yorůbá
ii. Dahun ibére abé eko
LitAlo ÄpagběNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Pa alo äpagbě
ii. Ko orin inu äpagbe náä
iii. Sq ohun ti eko inu alo náa ko wa
10EdeOnkä ni ědě Yorubá
151-200 Ookänlelégésän- án dé lgba
Ni Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Ka ônkä náä ni ědě Yorůbá yékéyeké
ii. Ka äwon Figo náä ni ědě Yorůbá
iii. Pe äwon Fígô. náa bí ó seye.
AsaOhun Elô inu iléNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Dáruko äwon ohun ělô inu ilé
ii. So ilô ôkôôkan wan
LitItan Akoni ile YorůbáNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Dárúko äwon akoni ilë Yorůbá
ii. Säläyé idí tíwan fijé akoni
iii. Dáhůn ibéěrě abé eko náä
11-12Agbéyëwô éko Ise Idaji Sáä Keji Lórĺ
Edě
Asä
Lítirésó
Agbéyëwô éko Ise Idaji Sáä Keji Lórĺ
Edě
Asä
Lítirésó
13Idánwô Sáä Kei lórí ědě Asä äti Lítírésô

Primary 3 Third Term Scheme of Work for Yoruba

   
 CLASSPrimary/Basic 3
 SUBJECTYoruba
 TERMThird Term
WEEKTOPICSLearning Objectives
1Idanwô Ikini Kaâbo Si Sâa KetaNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Dahun ibere
ii. Se âtunșe ti oye
2Âgbeyôwô ișë Săa keji Lori
Ede, Așâ âti Literaso
Ni Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Menuba âwon eko ti wón ti ko tële
ii. Dahun ibęre abe âyewo
3EdeAropô Oroko AfarajórukoNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. So oruko afarajóruko
ii. Ko iye âwon oro afarajóriko năâ
iii. Dăhun ibeere abe eko na
AsaIse Onâ ȘișeNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Dăruko âwon ișe onâ ti o wa
ii. Sâlâyć sóki lóri ôkôôkan wan
iii. Dăhun ibeërô abe ëko
LitOrin Akómoniwâ
-Omo tómo’ iyare lóju
– Eko dăra ę je ka Io
Ni Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Ko orin olorisirisi to dă le Ihuwâsi
ii. Fa kokó inu orin năâ yo
iii. Dâhun ibeere abe ëko
4EdeOnkâNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Ka onka nâ dăradăra
ii. Ko âwon Figo nâ yekeyeke
iii. Dăhun lbeëre abe ëkó naâ
AsaIpolówó Ojă ni ôđeNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Sâlâye âwon onâ Ip0lowo ôde ôni
ii. Dăhun lbeëre abe ëkó naâ
LitEre Omode
Kini n le je
Ni Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. So orișirisi ere omode ti o wâ
ii. Dăhun lbeëre abe ëkó naâ
5EdeImo Ęro kômputaNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. NI ôye lmô ęro kômputa
ii. Dăruko âwon eya ara imo ero naa
iii. Dăhun lbeëre abe ëkó naâ
AsaIranra-ęni-lówó ayë atijóNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Dăhun âwon onâ iranra-ęni- lowo
ii. Sâlâyë ânfââni to ro mă o
iii. Dăhun lbeëre abe ëkó naâ
LitAlă ApamoNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Pa âlo Apamo
ii. Fa kókó yo
iii. Dahun Ibëërë
6EdeOnka ni Ede Yoruba 170-190Ni Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Ka onka na yekeyeke
ii. Ko awon figo naa ni ede yoruba
iii. Dăhun lbeëre abe ëkó naâ
AsaIkinni ni Oniruru Ojo Odun AyeyeNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Salaye ikinni ni awon asiko kookan
ii. Salaye Ikinni ati idahun re
iii. Dăhun lbeëre abe ëkó naâ
LitEwiNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Ka ewi na
ii. Ke ewi na
iii. Fa koko inu ewi na yoo
iv. Dăhun lbeëre abe ëkó naâ
7Ägbéyewo éko lse Idaji Såä Keta Léri
Edé
Äsä
Litiréso’
Ägbéyewo éko lse Idaji Såä Keta Léri
Edé
Äsä
Litiréso’
8EdeIro faweli aramupo ati airanmupo a, e, o, o, u,
an, en, in, on, un.
Ni Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Daruko awon iro faweli aramupo
ii. Daruko awon fawelli airanmupo
iii. Dăhun lbeëre abe ëkó naâ
AsaImototo ara eni ati ayikaNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. So ohun ti imototo wa fun
ii. Ko orin imototo
iii. Dăhun lbeëre abe ëkó naâ
LitEwi Oriki lu EkoNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Ko nipa itan ilu eko
ii. Fa koko inu ewi naa yo
iii. Dăhun lbeëre abe ëkó naâ
9EdeIro Konsonanti b, d, f, g, gb, h, j, k, l, m, n, p, r,
s,s, t, w, y, (18)
Ni Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Ka iro konsonanti
ii. pe e tele oruko
iii. Dăhun lbeëre abe ëkó naâ
AsaAwoNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Da orisi awon awo ma
ii. Daruko awo ni orisirisi
iii. Dăhun lbeëre abe ëkó naâ
LitItan ArosoNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Ka itan na darâdara
ii. Fa koko inu iatn naa yo
iii. Dăhun lbeëre abe ëkó naâ
10EdeOnka ni ede Yoruba 181-200.
Ookanlelogoosan- an de igba
Ni Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Ka onka naa ni ede Yoruba yekeyeke
ii. Ko awon figo naa ni ede yoruba
iii. Pe awon figo naa bi ose ye
AsaOruko Amutorunwa ojo Oke Ige Ajayi DadaNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Daruko Amutorunwa tele oluko
ii. Se idamo idi ti okookan won fin je be
iii. Dăhun lbeëre abe ëkó naâ
LitEwi (Agbon)Ni Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Ka ewi nåå
ii. Fa koko inu ewi nåå yo.
iii. Dahun ibeëre abe ëkó naâ
11Edelwon Eyå ara Ifo lbére pepé äfipé
åsunsi ati åkånmolé
Ni Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Dåruko åwon eyå ara fun iro édé pipé
ii. Se idamo oköökan won
iii. Dăhun lbeëre abe ëkó naa
AsaAwon Kökoro åifojuriNi Opin Idanilekoo, Akekoo yoö le:
i. Dåruko ohun to le fa åisån si ara éniyån
ii. MO åwon idénå si kokörö äifojuri nåä
iii. Dăhun lbeëre abe ëkó naâ
12Agbéyewö éko Såä Keta Löri
Edé,
Asa
Literaso
i. Agbéyewö éko ti won ti ko fun igbaradi Idånwö
ii. Dăhun lbeëre abe ëkó naâ
13Idånwo Såä Keta

Recommended Yoruba Textbooks for Primary 3

Main Text

1. Bayo Aderanti et al, Ipinle Eko Ede Yoruba, Nelson, 2016.

2. Olu Owolabi, Yoruba Ode Oni, Evans, 2016.

3. K.O Akindele, Yoruba Dotun, Unique, 2016.

4. Yinka Folorunsho et al, Yoruba Alakobere, WABP, 2015.

5. Olubukola Boripenle, Ede Yoruba Ponbele, Foursquare Press, 2013.

6. S.M. Raji, Akotun Ede Yoruba Fun Ile Eko Alakobere, Extension, 2012.

7. J.F Odunjo, Alawiye, Learn Africa, 2016.

8. Okedokun Ayo, Omo Elede Ayoade, Okedokun & Assoc. 2017.

9. Williams O. Fatokun, Taiwo Ati Kehinde, University Press, 2014 

10. Olusola Fadiya et al, Yoruba Atomosona, Feather & Cars. 2013

 

Comprehension and Grammar

11.Akin Dahunsi, ABD, Fun Alakobere (twe Keta), Oburo Publishers, 2016.

12. Akinwunmi Atanda, lwe kiko Ede Yoruba, Laroded, 2014.

13. A. I. Alimi, Akotun Yoruba, Melrose, 2012. 

14. J.A., Akinniyi, Fitila Imo, Bitmap, 2016.

 

Handwriting
15. Abimbola, The Yoruba Language Class 3, Amsmart Consult, 2016.

16. Abimbola, Read, Write & Understand Yoruba now, Amsmart Consult, 2016.

17. Abimbola, The Yoruba Language Class Instructors Manual 3, Amsmart Consult, 2016.

18. Babatunde Tijani, Learn How to Read and Write Yoruba.

 

Workbook
19. Olu Owolabi et al, Yoruba Ode Oni Work Book, Evans, 2016.

20. Bayo Aderanti et al, Ipile Eko Ede Yoruba, Nelson, 2016.

21. A.I Alimi, Akotun Yoruba, Melrose, 2012.

22. Kunle Akinsemoyin, Agbo Odun, WABP, 2015.

23. Kunte Akinsemoyin, Awon Akuko Meji, WABP, 2015.

24. Lagada- Abayomi, Ayoka Ati lgi Iroko, Tanus Books, 2017.

25. Kunle Akinsemoyin, Mumuni Ati Kete Omi Re, WABP, 2015.

SyllabusNG

© 2024 Created with Page 5 Digital
Download Syllabus