JSS2 Yoruba Scheme of Work

Download the Junior Secondary School 2 (JSS2) Scheme of Work for Yoruba Language to serve as a guide for educators

Home » JSS2 Scheme of Work » JSS2 Yoruba Scheme of Work

About JSS2 Yoruba Scheme of Work

In Junior Secondary School 2 (JSS2) in Nigeria, students learn about the language and culture of the Yoruba people. Yoruba is a major ethnic group in Nigeria. It is a big part of Nigeria’s southwestern culture, spoken by millions of people.

In class, they study how to speak, read, and write Yoruba, as well as learn about Yoruba traditions and stories. By studying Yoruba, students not only learn a language but also learn about the history and customs of the Yoruba people, which helps them appreciate Nigeria’s diverse cultures and strengthens their sense of identity.

Assessment Guide

In junior secondary schools, how students are assessed in Yoruba can differ from school to school. However, typically, they are evaluated through tests or oral quizzes (Continuous Assessment Tests) and end-of-term exams.

Grading usually follows a scale from A to F, with A representing excellent performance, typically scoring around 70% or 80%, and F indicating failure, usually below 40%.

Download JSS2 Yoruba Scheme of Work

jss2-yoruba-scheme-of-work

Know what’s expected of you as an educator

Download the National Associations of Proprietors of Private Schools(NAPPS) for JSS2 Yoruba

JSS2 First Term Scheme of Work for Yoruba

 NATIONAL ASSOCIATION OF PROPRIETORS OF PRIVATE SCHOOLS (NAPPS) SCHEMES OF WORK FOR JUNIOR SECONDARY SCHOOLS
 Yoruba Scheme of Work for Junior Secondary School 2(JSS2)
 ClassJ.S.S 2
 SubjectYoruba
 TermFirst Term
WeekTopicBreakdown
1ÈDÈ: Sílébù Èdè YorùbáÀKÓÓNÚ IŚË
1. Oríkì sílébù .
2. Ìhun sílébù (F, KF, Kos (N)
3. Pípín õrõ sí sílébù
2ÀŚÀ: Êsìn Ìbílê YorùbáÀKÓÓNÚ IŚË
1. Pàtàkì Êsìn Láwùjô Yorùbá
2. Ìgbàgbö Àti Èrò Àwôn Yorùbá Nípa Olódùmarè
3. Ipò Olódùmarè
4. Òrìśà Ilê Yorùbá
5. Êsìn òde òní:
* Mùsùlùmí
* Ômôlëyìn Jésù
3LÍTÍRÈŚÕ: Àśàyàn Ìwé Ìtàn Àròsô Ôlörõ GeereÀKÓÓNÚ IŚË
1. Ìsônísókí ìśêlê inú ìtàn abáyému
2. Êkö àti kókó õrõ tó súyô àti ìbáyému õrõ tó ń lô láwùjô, (bí
àpççrç ipò/ ìpín obìnrin láwùjô, ìkôlura êsìn, ômôlúàbí, ìtöjú
àyíká, ìlera, ààrùn éèdì/ rômôlöwölësê abbl)
3. Êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá
4. Ìlò èdè:
(a) Ônà èdè
– Àfiwé
– òwe
– Àkànlò èdè
(b) Àwítúnwí
– Ìfìrómõrísí
– ìfohungbohùn abbl
4ÒÝKÀ: Oókanléláàádöjô dé igba (151 – 200).Kíka owó Náírà ÀKÓÓNÚ IŚË
Òýkà láti Oókanléláàádöjô dé igba (151-200). Òýkà owó
náírà b.a. náírà kan, náírà méjì, ogún náírà, ôgbõ náírà abbl
5ÈDÈ: Oríśiríśi Gbólóhùn (Ìhun)ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Oríkì Gbólóhùn
2. Oríśiríśi Gbólóhùn
* Alábödé
* Alákànpõ
* Oníbõ
6ÈDÈ: Àmì OhùnÀKÓÓNÚ IŚË
1. Oríkì àmì ohùn
2. Àlàyé lórí oríśi ohùn Yorùbá mëtêêta àti àmì wôn
i. Ohùn àárin – (a kì í fi í hàn lórí õrõ)
ii. Ohùn ìsàlê –
iii. Ohùn òkè –
3. Fáwëlì àti oríśiríśi àmì ohùn kõõkan lórí fáwëlì kõõkan. Bí
àpççrç: à, a, á, è, e, é, abbl
4. Àmì ohùn lórí õrõ onísílébù kan. B.a: bá, dà, kan abbl.
7ÀŚÀ: Ìranra-çni-löwöÀKÓÓNÚ IŚË 1. Èsúsú
2. Àjô
3. Õwê
4. Àáró
5. Àrokodóko
6. Çgbë aláfôwösowöpõ òde òní.
8LÍTÍRÈŚÕ: Àśàyàn ìwé eré-onítànÀKÓÓNÚ IŚË
1. Ibùdó ìtàn
2. Àhunpõ ìtàn
3. Àśà tó súyô
4. Kókó-õrõ
5. Ìfìwàwêdá
6. Ìlò èdè
9ÀŚÀ: Òýkà ôjö àti ośù ní ilê YorùbáÀKÓÓNÚ IŚË
1. Òýkà àwôn ôjö tí ó wà nínú õsê. Ìtàn tí ó rõ mö ôn. Ôjö Ajé,
Ìśëgun, Ôjörú, Ôjöbõ, Çtì, Àbámëta.
2. Àwôn ośù tí ó wà nínú ôdún: Śërë, Èrèlé, Erénà, Igbe, Èbìbí,
Okúdù, Agçmô, Ògun, Ôwëwê, Õwàrà, Belu, Õpç.
10ÈDÈ: Aáyan ÒgbufõÀKÓÓNÚ IŚË
1. Oríkì aáyan ògbufõ
2. Ìtönisönà lórí bí a śe ń śe aáyan ògbufõ
3. Śíśe aáyan ògbufõ çlëyô õrõ láti èdè Gêësì sí Yorùbá
4. Túmõ gbólóhùn kéèkèèké láti èdè Gêësì sí Yorùbá.
11ÀŚÀ: Oúnjç Ilê YorùbáÀKÓÓNÚ IŚË
1. Oríkì oúnjç
2. Oríśiríśi oúnjç
3. Bí a śe ń śe oúnjç kõõkan.
4. ìsõrí ìsõrí oúnjç afáralókun àti amáradán
5. Àfiwé oúnjç àtijö àti ti òde òní.
12ÈDÈ: GbólóhùnÀKÓÓNÚ IŚË
1. Ìbéèrè
2. Àlàyé
3. Àśç
13ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ 
14ÌDÁNWÒ 

JSS2 Second Term Scheme of Work for Yoruba

 TermSecond Term
WeekTopicBreakdown
1LÍTÍRÈŚÕ: Àśàyàn ìwé (Ewì Àpilêkô)ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Àwôn ewì tó wà nínú ìwé tí a yàn
2. Kókó õrõ b.a. ìwà ènìyàn; àwôn êdá mìíràn tí kì í śe ènìyàn, õrõ tó ń lô
láwùjô,, ìkôlura êsìn, ipò obìnrin, ètò ôrõ-ajé, ìśakô/ ìśabo –
gbogbolômô, éèdì.
Àkíyèsí: Ó pôn dandan láti yan ìwé ewì tí ó ní àwôn àkóónú kókó õrõ
wõnyí
3. Ônà èdè àti ìsôwölo-èdè.
2ÀŚÀ: Ogun àti ÀlàáfíàÀKÓÓNÚ IŚË
1. kí ni ogun? Kí sì ni ìdí tí ó fi máa ń wáyé?
2. Ogun Yorùbá láyé àtijö
– orúkô ogun b.a. jálumi, kírìjí abbl
– Àwôn jagunjagun b.a. Ìbíkúnlé, Ògúnmölá, Ògèdèýgbé abbl
– Ohun èlò ogun b. a. ôfà, ôkõ, idà, ìbôn, oògùn.
3. Àýfààní ogun jíjà; õnà ìdáàbòbo ìlú çni, láti kó ìlú çni lërú, abbl
4. Àléébù ogun nípa ôsë tó ń śe
– Dá õtá sílê
– Run ìlú
– Fa ìyàn, abbl
5. Õnà láti dëkun ogun jíjà.
– Yíyàgò fún aáwõ.
3ÈDÈ: Àtúnyêwò Ìsõrí Õrõ – Õrõ-Orúkô àti Õrõ-ÌśeÀKÓÓNÚ IŚË 1. Àlàyé lórí õrõ-orúkô
2. Iśë tí õrõ-orúkô ń śe nínú gbólóhùn
3. Àlàyé lórí oríśiríśi õrõ-orúkô
4. Àlàyé lórí õrõ-ìśe
5. Iśë tí õrõ-ìśe ń śe nínú gbólóhùn.
4ÀŚÀ: Òýkà- Õtàlénígba-ó-dín mësàn-án dé õödúnrúnÀKÓÓNÚ IŚË
Òýkà láti Õtàlénígba-ó-dín mësàn-án dé õödúnrún (251 – 300). Kíkà
260 = Õtàlénígba
280 = Õrìnlénígba
300 = Õödúnrún
5ÈDÈ: Fónëtíìkì – Àpèjúwe ìró KöńsónáýtìÀKÓÓNÚ IŚË
1. Köńsónáýtì: b, d, f, g, gb, h, j, k, l, abbl
2. Àpèjúwe ìró köńsónáýtì
– ibi ìsçnupè
– õnà ìsçnupè
Ipò tán-án-ná
6ÀŚÀ: Ogun àti ÀlàáfíàÀKÓÓNÚ IŚË
1. Àýfààní ogun jíjà; õnà ìdáàbò bo ìlú çni, láti kó ni lërú abbl
2. Àléébù ogun nípa ôśë tí ó ń śe
– Dá õtá sílê
– Run ìlú
– Fa ìyàn abbl
3. Õnà láti dëkun ogun jíjà
– Yíyàgò fún aáwõ.
7ÈDÈ: ÒweÀKÓÓNÚ IŚË
1. Oríkì òwe
2. Oríśiríśi òwe
3. ìlò òwe
4. Ìwúlò òwe
8ÈDÈ: Àtúnyêwò ìsõrí õrõ-ìśeÀKÓÓNÚ IŚË
1. Iśë tí õrõ-ìśe ń śe nínú gbólóhùn
* õrõ- ìśe çlëlà
* õrõ-ìśe aláìlëlà
* õrõ-ìśe agbàbõ
* õrõ-ìśe aláìgbàbõ
* õrõ-ìśe alápèpadà
* õrõ-ìśe aśèbéèrè, abbl
9ÈDÈ: Fónëtíìkì – Àpèjúwe Ìró FáwëlìÀKÓÓNÚ IŚË
1. Fáwëlì:
* Àránmúpè – an, çn, in, un, ôn
* Àìránmúpè – a, e, ç, i, o , ô, u
2. Àpèjúwe ìró fáwëlì
* ipò ahön
* ipò ètè
* ipò àfàsé
10ÀŚÀ: Ìpolówó ÔjàÀKÓÓNÚ IŚË
1. Ìdí tí a fi ń polówó ôjà
2. Bí a śe ń polówó ôjà: b. a. êkô tútù, ç ç jçran êkô.
3. Ôgbön ìpolówó ôjà ní ayé àtijö àti òde òní. B.a. ìpolówó ôjà lórí rédíò,
tçlifísàn, ìwé ìròyìn, ìpàtç, ìkiri abbl.
11ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ 
12ÌDÁNWÒ 

JSS2 Third Term Scheme of Work for Yoruba

 TermThird Term
WeekTopicBreakdown
1ÀŚÀ: ÌsômôlórúkôÀKÓÓNÚ IŚË
1. Ìgbàgbö Yorùbá nípa bí orúkô śe śe pàtàkì tó (orúkô
ômô ni ìjánu ômô, orúkô a máa ro ômô) orúkô rere.
2. Ètò ìsômôlórúkô b.a lílo ìrèké, oyin, àádùn, abbl (àwôn
ohun èlò ìsômôlórúkô).
2ÈDÈ: ìsõrí õrõ
Õrõ aröpò orúkô àti õrõ aröpò afarajorúkô
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Oríkì õrõ aröpò-orúkô
2. Àbùdá õrõ aröpò-orúkô
3. Àlàyé lórí õrõ aröpò-afarajorúkô àti wúnrên rê.
3ÒÝKÀ: Õödúnrún dé Êëdëgbêta (300 – 500)ÀKÓÓNÚ IŚË
Òýkà láti Õödúnrún dé Êëdëgbêta (300– 500)
320 = Okòólélöõödúnrún
400 = Irínwó
460 = Õtàlénírínwó, abbl
4ÀŚÀ: ÌsômôlórúkôÀKÓÓNÚ IŚË
1. Ètò ìsômôlórúkô, bí a śe ń lo àwôn ohun èlò
ìsômôlórúkô bí i obì, orógbó, ataare, oyín, ìrèké abbl fún
ìwúre
2. Oríśiríśi orúkô
* Àbísô
* Àmútõrunwá
* Oríkì
* Àbíkú
* Ìnágijç, abbl.
5ÈDÈ: Aáyan Ògbufõ (ôlörõ geere àti ewì)ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Títúmõ àyôlò ôlörõ geere kéèkèèké ní èdè Gêësì sí èdè
Yorùbá
2. Títúmõ àyôlò ôlörõ geere ní èdè Yorùbá sí èdè Gêësì.
3. Títúmõ ewì ní èdè Gêësì sí èdè Yorùbá.
6LÍTÍRÈŚÕ: Lítírèśõ AlohùnÀKÓÓNÚ IŚË
1. õgangan ipò:
– ìtumõ
– Àbùdá rê
 Akópa (òśèré/ olùgbö)  Àkókò ìśeré
 Ibi ìśeré
 Ìwúlò
 Ohun èlò – orin
 Ìśêlê
 Ìfarafojúsõrõ
2. Õrõ-ìśe tí a fi gbé wôn jáde bí i pípè, sísun, kíkô, dídá,
mímu abbl.
7ÈDÈ: Ìsõrí – Õrõ
Õrõ-Atökùn àti õrõ-àsopõ
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Õrõ-Atökùn
2. Õrõ – àsopõ
3. Àwôn wúnrên õrõ-àsopõ
8ÀŚÀ: Ìtêsíwájú Lórí Êkö-IléÀKÓÓNÚ IŚË
1. Ìwà ômôlúàbí
 Ìkíni, ìbömôwí
 Ìbõwõfágbà
 Ìgböràn
 Níní sùúrù
 Iśë inú ilé śíśe
 Jíjë ômôlúàbí sí òbí àti àwùjô
2. Dídëkun ìwà ìkà sí ômôlàkejì
 Gbígba àlàáfíà láàyè
 Fífi ara çni sí ipò ômôlàkejì
 Agbófinró abbl
9ÌBÁŚEPÕ LÁÀRIN ÈDÈ ÀTI ÀŚÀÀKÓÓNÚ IŚË
1. Ìwúlò èdè
2. Èdè gëgë bí òpómúléró àśà
10ÀŚÀ: Oge ŚíśeÀKÓÓNÚ IŚË
1. Pàtàkì oge sis
2. Oríśiríśi õnà tí a ń gbà śoge
Ayé àtijö;
 Ara fínfín
 Eyín pípa
 Tìróò lílé
 Làálì/ osùn kíkùn
 Irun dídì, irun fífá, irun gígé, irun kíkó
 Ilà kíkô abbl
3. Oge śíśe lóde òní;
 Ètè kíkùn
 Irun díndín
 Ihò méjì lílu sí etí kan
 Imú lílu
 Aśô tó fara sílê
 Bàtà gogoro abbl
11ÈDÈ: Ìsõrí Õrõ
Õrõ-àpönlé àti õrõ-àpèjúwe
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Oríkì õrõ-àpönlé
2. iśë tí õrõ àpèjúwe ń śe nínú gbólóhùn.
12ÀTÚNYÊWÒ ÊKO 
13ÌDÁNWÒ 

Recommended Yoruba Textbooks for Junior Secondary School 2

The recommended textbooks for Yoruba in J.S.S.2 include:

Literature Text (JS1 – 2) 

  • Ilu Alagbara by Oluwanisola Yusuf – Gstar Publishers
  • Owo Ibobe by Wale Mabogaje – Divine Favour Publishers 
  • Adiitu Laye by Bade Ojuade – Rasmed Publishers
  • Ogede Pipon by Doyin Abegunde – Arisilejoye Publishers 
  • Ewi fun Awon Odo 

Textbooks (JS1 -3) 

  • Eko Ede Yoruba Titu Iwe Kininni (JS1) by Oyebamiji Mustapha et al 
  • Eko Ede Yoruba Titun Iwe keji (JS2) by Oyebamiji Mustapha et al 
  • Litereso atI Asa Yoruba JS3 by Mobolaji Arowosegbe 

Litereso Texts 

  1. Sisi Oloja by Olajumoke Bamiteko 
  2. Subu Sere by Lasunkanmi Tela 
  3. Olu Omo by D. O. Adisa 
  4. Atiteebi by Diipo Gbenro 
  5. Ijinle Arofa Yoruba  by Meedogbon Kola Ajiboye 

Text Book 

Eko Ede Yoruba Titun Iwe keta (JSS3) 

Litereso ati Asa Yoruba 

Mobolaji Arowosegbe

Professional Certification

CIBN Syllabus

CITN Syllabus

APCON Syllabus

Company

Career

Media Kit

SyllabusNG

© 2024 Created with Page 5 Digital
Download Syllabus