Request a Demo

Edit Template

Primary 1 Yoruba Scheme of Work

Download the Unified Basic 1 Scheme of Work for Yoruba, to serve as a guide for educators and primary school teachers.

Home » Primary 1 Scheme of Work » Primary 1 Yoruba Scheme of Work
primary-1-scheme-of-work

About Yoruba Scheme of Work for Primary 1

The Basic Science for Primary 1 serves as a tool used to introduce the pupils to science. The topics are split into broad themes: Living and Non-living things and each of these themes covers different topics such as Energy, Water, Soil, colour, machines, transportation etc will be treated. These selected topics aim to make them familiarize themselves with Living and non-living things.

Instructors should communicate these new terms properly to the student, to ensure proper assimilation. Examples should also be given and they should be asked to relate it to real-life experience.

Primary 1 First Term Scheme of Work for Yoruba

 LAGOS STATE GOVERNMENT MINISTRY OF EDUCATION UNIFIED SCHEMES OF WORK FOR PRIMARY SCHOOLS.
 Yoruba Scheme of Work for Primary/Basic 1
 CLASSPrimary/Basic 1
 SUBJECTYoruba
 TERMFirst Term
OSEORI OROERONGBA
 Idanwò Ikini kàbì Si Saa kinniNi òpin idanilekoo akékò yò Ie
i. dahun ìbéèrè abe eko
ii. Se àtunse abe eko
1EdeDidâruko àwon nnkan inu yàrâ ikàwéNi òpin idanilekoo akékò yò Ie:
i. Didâruko àwon nnkan inu yàrâ ikàwé
ii. Da àwon nkan inu yàra ìkàwé mo ni okookan
iii. Sàlàyé ìwulò nìkan inu yàra ìkàwé naa
AseIkini ni ilè YorùbàNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. Sàlàyé lori pàtàkì ìkini ni ilè Yorûbâ
ii. Dirüko orisirisi ikini ti o wà àti ìdâhùn rè
iii. Se àfihàn bi omobìnrin àti omokûnrin se n’ ki àgbàlagbà àti òbi won
LitKiki àwon Orin kéé kéé kéé
Imot0to Ibawi akonilogbon
Ni òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. korin kée kèe kéé gégé bi ìsiniléti fun ìdinileko
ii. Sàlàyé Iori ìwulò orin kòòkan
iii. Dahùn ibéèrè abé èko
2EdeOnka Edè Yorùba’ lati Ookan dé EéwàNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. Se àlàyé Iori ohun ti Onkà èdè Yorùba jé
ii. Ka ònkà léti 0okan titi Eéwàa’ (1-10) ni sise-n-tele
iii. Dâhùn ibéèrè abé èko na
AseIwa rereNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. So ni pàto ohun ti iwà rere ro ma
ii. daürdko àwon iwà rere ti wà
iii. Sàlàyé awon ànfààni ti o mo ro ninuu iwà rere,
LitOrin IkiloNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. korin ikilô tí owa fun äwon omodé
ii. jo so orin ti won ba ko lori ikilo
iii. daruko awon ohun ilo fun ijo jijo
3EdeKiki Alifabeeti čde YorubáAkékòo y0ò lè;
i. Dá awon äwôrán kôôkan mo
ii. Pe Oruko äwon ôwôrán kôôkan to won ye wô
iii.Dahun ibere abe eko naa
AsaÄwon ojo ninu oseAkékòo y0ò lè;
i. Dáruko äwon ojo kookan tí o wa ninu ose
ii. Pe awon ojo kôôkan ni sise-n- tele
iii. Ko orin to ro ma kika ojo inu ose pelu ohun didun

LitOrin IdárayaAkékòo y0ò lè;
i. Korin kéékëěké lóri eré idárayá
ii. Parapo fún kíko orin eréidarayá
iii. so iwulo orin ere idaraya tin won ko
4Edelsorô-n-gběsi láarin akekooAkekoó Yóô Lě;
i. Säläyé ohun ti i;ôrôngběsi je
ii. Beere oruko enikookan won laaarin ara won
iii. Ba ara won soro lori koko oro nkan B.A ounje ti won feran ju
AsaImototo ara eniAkékòo y0ò lè;
i. salaye ohun to imototo je
ii. safihan itoju ara
iii. ko orin imototo
iv. dahun ibeere abe eko
LitKiko orin nipa iwa rereAkékòo y0ò lè;
i. ko orin nipa iwa rere
ii. so iwulo orin tin wan ko lori iwa rere
iii. daruko die lara iwarere ti oye ki omode ma hu niwa
5EdeSíse nnkanAkékòo y0ò lè;;
i.Gbo oro ase tuntun ti yoô si múlô
ii. Pe oro tí ó gbo ni sisê-n-têlé
iii. Se àfihàn oro ti ó gbo ni okookan
AsaOjuse Ebí ninu IdíléAkékòo y0ò lè;;
i. Dáruko àwon ti won parapô die bi
ii. Sàlàyé ni pàtó ojúse eni ko okan nínu ebi tàbi idílé
iii. Dáhün ibéêrê ti ó jeyo ni abé Qké
LitOrin kéékêêké ati ijoAkékòo y0ò lè;;
i. Ko láti jó si àwon orin tiwan ko ni ibámu pêlu ilü re
ii. Dahun ibéêrê abe êko
6EdeKikà Alífabéêti Edê Yorübá A-GBAkékòo y0ò lè;
i. Ka alífâbéêti ni okookan láti le rántí ohun ti wanti ko
ii. Dahun ibéêrê abé eko gégé bi’ isé sise.
AsaIkiniNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. Dáruko àwon orísirisi igbà to ni se pêlu Ikíni
ii. So bí a se n kini fún àsikô tàbí àkókô kookan
iii. Sôrô Iórí idáhün ti ó wà fún ikini kôôkan
iv. Dáhün ibéérê abe êko náà
LiterasoOrin kéékêêké fun ibawiNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. ko orin ibawi kéékêêké fun omode
ii. So bí a se n bofo fagba
iii. Dáhün ibéérê abe êko náà
7EdeIdanranwo Fun Idaji Saa KiniNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
Dáhün ibéérê abe êko náà
AsaIdanranwo Fun Idaji Saa KiniNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
Dáhün ibéérê abe êko náà
LitIdanranwo Fun Idaji Saa KiniNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
Dáhün ibéérê abe êko náà
8EdeKiko Alifabëêtì èdè YorubaNi òpin idanilekoo akékò yò Ie
i. Da àwon orisìirisi mô pèlu oruko
ii. Pe orisìirisi oruko àwòran kòòkan
iii. Dahun ibéère ti o ba jeyo ni abé èko
AsaImìt6t6 AyikaNi òpin idanilekoo akékò yò Ie
i. sàlàyé ohun ti ìmototo jé
ii. sàfihàn ìtoju ara
iii. Ko orin ìmòto
iv. Dahùn ìbéèrè abé êko
LitEré Osupa sise ni aléNi òpin idanilekoo akékò yò Ie
i. Se àlàyé Iori eré osupa sise ni alé
ii. Daruko orisìiri eré osupa sise ti owa
iii. Ko ara jo Iati se àfihàn eré òsûpa
9EdeItèsiwaju ninu kikà Alifabéètì èdè Yorûba’
H-Q
Ni òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. Ka létà alifabéètì èdè Yorùba’ lati H-Q
ii. Pelétà alifabeti pèlü àwon oro ti a sèda’
iii. Da àwon alifâbéèti kookan mo nipa fifi won pe àwòran ti o ro mo.
iv. Dahun ibéèrè abé èko na
AsaIkini fün Isé ni ilè Yorùba’Ni òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. Dirüko onirüurü ise ti o wà ni ilè Yoruba
ii. So ni pàto Ikini ti owà ni ilè Yorübü
iii. Ménuba ìdahun ti òkòòkan ni.
LitAwon Ewi kéékéekééNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. Ké ewi kéé kèè kéé
ii. Fa koko ninü ewi yi,
iii. Dahùn àwon ibéèrê abé êko
10EdeAgbéyewô Ise Saa Kini Lori EdeNi òpin idanilekoo akékò yò Ie
Se àgbéyewo awon eko ti wan ti ko
IIAgbéyewô Ise Saa Kini Lori AsaNi òpin idanilekoo akékò yò Ie
Se àgbéyewo awon eko ti wan ti ko
III
Agbéyewô Ise Saa Kini Lori Lit
Ni òpin idanilekoo akékò yò Ie
Se àgbéyewo awon eko ti wan ti ko
13Idanrawò Fun Saa, kinniIdanrawò Fun Saa, kinni

 

Primary 1 Second Term Scheme of Work for Yoruba

 CLASSPrimary/Basic 1
 SUBJECTYoruba
 TERMSecond Term
OSEORI OROERONGBA
1
Igba kini
Igba keji
Igba keta
Edë Așâ Literćșo Idănwô Ikini kăâbo
Si săâ keji

Ni òpin idanilekoo akékò yò Ie:
i. Dăhun ibere abe eko
ii. Se âtunșe abe eko

2
Igba kini
Igba keji
Igba keta
Edô Âsâ
Litirćșo Âgbćyëwô lșe săâ Kinni
Ni òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. Yę âwon eko săâ kinni wô dăadăa
ii. Dăhun ibćere abe âyewô năâ
3EdeDidăruko nnkan âyikă ilć-iwćNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. Dăruko âwon nnkan âyikă ile-iwć ni ôkôôkan
ii. Șâlâyć iwulô âwon nnkan ti wăn dăruko ni sise-n-tele
iii. Dăhun ibere abę ëko naa
AsaOrłsnrisi Eran ôsin ni ile YorubăNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. Sâlâyć ohun tie, ran Ôsin jë
ii. Dăruko âwon orișiirisi ęran Ôsîn ti ó wâ ninu ilć âti âynka’ wa
iii. Se âpëjuwe bi ôkôôkan șe maa n ri
III, LitłrëșqKiko orin akóniniwâ ni ëdë YorubăNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. ko orin akoniniwâ ni ëde Yoruba’
ii. Sâlâyć pâtâki kiko irufe orin yii
iii. Dahun ibćërč abe eko
4EdeItęsiwaju ninu kikâ Alifăbëëti ëdë Yorubă
H-Q
Ni òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. Ka leta alifâbëti ëdë Yoruba’ lăti A-GB
ii. Pe letâ ălifăbâti pëlu âwon oro H-Q gëgë bi a ti șëda’
iii. Da âwon ălifabeëti kookan mo nipa fifi wăn pe âwôrăn ti ó ro ma
iv. Dăhun ibëerë abć čkó năâ
ASAOunję Ile waNi òpin idanilekoo akékò yò Ie:
i. Daruko awon ounje ile wa
ii. Salaye iwulo ounje kokan
iii. So ilu ti ounje onje kokan ti a daruko
LitEwi kika ni ede yorubaNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. Ka Ewi Ibowofăgbă
ii. Ka ewi năa bi o se ye
iii. Fa koko inu ewi na yoo
iv. Dăhun ibëerë abć čkó năâ
5EdeOrikå låti 11-20Ni òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. Ka orikä läti ookan – ééwåå (1 -10) gégé bi irånti
ii. Ka orikå låti ookanlåå Ogun (11-120) gégé bi itesiwaju
iii. Lo idi gégé onkå fun äläyé
AsaEré IdårayåNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. Dåruko orisirisi äwon eré idårayå
ii. Ko bi eré idåraya se n’ wäyé
iii. Ko orin eré idåraya’ bi eré bé n’ se wäyé
LitAlo pipa ni ile Yorüba’Ni òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. So Ohun ti ålo pipa jé
ii. Dåruko orisi onä méji ti o pin si
iii. Pa oniruru ålo åpamö
iv. Dåhun lbééré abé éko
6EdéÄlifäbééti édé Yorübå kiti P-YNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. ka äwon Älifåbéeti édé Yorübå låti P-Y gégé bi Itesiwåju
ii. Pe åwon Iro koökan ni sise-n-tele
iii. Dåhün lbééré tiobåjeyo ni abé eko
Äsålwä omoluäbiNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. So ni påto Ohun ti lwå omoluabi jé
ii. Sålåyé ni soki inifååni ti o wa fun wa omoluäbi ni hihü.
iii. Dåhün lbééré abé eko.
LitiresoOrin kikoNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. ko Orin to ro mo omo rere
ii. Jo si orin kookan tiwan ba ko
iii. Se ise ti o bå jeyo låbé éké
7Idånrawö Fun Idaji Sää lori Edé, Äså ati
Literééso
Ni òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. Dåhün ibééré abé eké nåä pelu atunse tunse ti oye
8EdeÄliffåbééfi låti A-YNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. ko Äliffåbéeti édé Yorubå ni létå nlå ati kékeré
ii. Da létä nlå ma yätö si kékeré
iii. Pe létå koökan pelu äwörån ti o båmu.
AsaOjuse Ebi /ldiléNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. Sälåyé eni ti olori ebi jé
ii. Säläyé ojuse omo si obi åti äwüjo
iii. Dåhün ibééré abé eko
LitOrin kiko Ióri ObíNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. korin orĺsiirishi Iori ôbi
ii. So pataki orin tí won ko
iii. Dahun ibére tí o wa labé eko
9EdeKiko Oro ati idakeji ni edč YorubäNi òpin idanilekoo akékò yò Ie,
i. Ronu jinle Iórĺ orisiírisi,oro ati idäkeji
ii. Ko orĺsĺrishi äwon oro tí ó ni idäkeji jáde
iii. Se ise lori ibeereti ó je yo Iori ise nää,
Asalkini ni äsiko isejeNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. Daruko Oni Rufuru isele ti’ o máa wáyé ni ile Yorubá
ii. Ménuba äwon ikini ti owa fun okookan ati idahun re
iii. Ise sise ni abé oko náä
LitAlo ÄpagběNí ôpin Idánilékôo, akékôéyőô lë;
i. So nísoki ohun ti älo Apaagbë jé
ii. Pa okan-o-jokan alo äpagbě
iii. Dáhůn ibéërë abé ëko
10EdePípe Iro ëděNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. Säläyé ohun ti irő ědě pípě jé
ii. Dáruko Ônä méji ti iro ëdë pi’n si
iii. Ko äpeere awon iró náä jáde,
AsaIwä rereNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. Sonísókĺ ohun ti iwä rere
ii. Dáruko oníhuhu lhůwäsĺ tí ó ro mo Iwä rere
iii. Se eré ránpe gége bi äfihän iwä rere
LitÁrôso oIórô geere lőrí AjáNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. So bi irúfé eranko ti ajá jé
ii. Säläyé iwúlô ajá nínú ilé iti lóko
iii. Dárúko ilu tí Ó férän ajá iti idi tí wan fi férän re.
11Agbéyewô Ise Sáä Kejl Lórĺ Edě, Asa ati LítírésôNi òpin idanilekoo akékò yò Ie
• Dáhun lbéérë abe ëké lóri édë asa ati Lítírésô
12Idánrawô Fun Saa kejiIdánrawô Fun Saa keji

Primary 1 Third Term Scheme of Work for Yoruba

 CLASSPrimary/Basic 1
 SUBJECTYoruba
 TERMThird Term
OSEORI OROE’RO’NGBA’
1, igbâ Kînni
igbâ Kejl
igba Keta
Ede Așa Litireșo Îdănwo ikîni kăâbo si sââ kejiNi òpin idanilekoo akékò yò Ie
i. Dahun ibeere abe eko
ii. Șe âtunșe abe ek0,
2, igbâ Kinni
igbâ Kejł
igba Keta
Ede Asa Litireso Âgbeyewo Ise’ Sâ KinnłNi òpin idanilekoo akékò yò Ie
i. Ye awon ęko săâ kinnî wo dadda
ii. Dăhun ibere abe’ âyewo na’
3EdeSișe NnkanNi òpin idanilekoo akékò yò Ie
i. Gbo ohun ti Oluko ba’ ni ko se
ii. So ohun ti o gbo Ieralera’
iii. Șô nnîkan ti Olóko ba’ ni kose
AsaItęsiwaju kłniNi òpin idanilekoo akékò yò Ie
i. So bi atin’ kini ni; orisirisi âkoko to wâ.
ii. So pâtâkî Ikîni ni âwuję ile Yorubă
iii. Da’hun Ibeere ti oję yo ni abe- eko
LitOrin era IdarayaNi òpin idanilekoo akékò yò Ie
i. ko ara won jo si abe igi Ôrombo’ fun igbaradi orin kiko
ii. JÓ si orin ti won n’ ko pelu âtewo
iii. Dăhun Ibeere abe eko
4EdeSiso oro onilęta pôNi òpin idanilekoo akékò yò Ie
i. So Ôro onîletâ meta po nipa ti tele llânâ F+K+F
ii. KO oniruuru âpęęrę oro oniletâ meta jăde.
iii. Dăhun ibëre abe’ eko năâ
AsaOrisirisi eso ile waNi òpin idanilekoo akékò yò Ie
i. Dăruko awon eso ilë wa
ii. So patâki eso kookan
iii. Pin won si Ôwoowo
iv. Dahun Ibere abc eko
LitAko PupaNi òpin idanilekoo akékò yò Ie
i. Pa oniruuru alo apamö ati apagbé
ii. wa idahon si åwon alo köökan ti won ba’ pa
iii. Dăhun ibëre abe’ eko năâ
5EdeIsorongbesi laarin Oluko ati akekooNi òpin idanilekoo akékò yò Ie
i. Bééré ibéeré Iååårin Olükö si Akéköö
ii. Se iberé Iåårin akéköö si Oluko
iii. Dåhün itåkuroso ti o wåyé laaarin awon méjééji
AsaImototo: Ara FiföNi òpin idanilekoo akékò yò Ie
i. So bi a ti se 1e fo enu wa
ii. Sålåyé åwon oniruuru önå ti a Ié gbå fo enu wä ati påtåki fifo enu
iii. Dåråko åwon ohun elo fifo enu.
LitOrin kikoNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. ko orin kan påto
ii. Fa koko’ inu orin nää
iii. Gba läåyé akéköö Iäti ko orin nää däadåa
iv. Dåhün ibééré abé ök6
6Edeönka Iåti ookanlélogun — ogoji (21-40Ni òpin idanilekoo akékò yò Ie
i. ka önkå Iäti ookanlélogun-Ogoji (21-40) nipa sise åfikun åti åyokurö
ii. Se åmulo eele ati eédin
iii. Ka onka dåadaa Iäti Ié da’ a mö
AsaIjo inu oseNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. So ni päto ltån ti rö mö ojo kookan
ii. Pe åwon ojö nåå lokookan
iii. Fi ojo kookan korin ni teletele
LitEwiNi Opin danilekpp. Ak9kQQ Yoo Le; ka ewi nää dåadåa
i. Ka ewi na daada
ii. Pe örö inu ewi nåä jade yékéyéké
iii. Fa koko inu ewi na yo
7EdeAwon awo olorisirisiNi òpin idanilekoo akékò yò Ie:
i. Dåruko oniruuru’ Äwö ti o Wå
ii. Se iwulo åwon åwo kookan
iii. se kikun åwon åwö nåå sinu iwe wan
AsaIwa rereNi òpin idanilekoo akékò yò Ie;
i. Sålåye’ åwon iwåti ko fi iwa rere hän
ii. Söro lori åbajåde ailehuwå rere abi ewu to wå Iori re
iii.Darüko awon iwä ti kö tö läti hü.
iv. Dähun ibeere abe ekö
LitEwi Iori ise ni öogün iséNi òpin idanilekoo akékò yòo Ie;
i. Ka ewi nåå däadåa pélu édé to jinna
ii. Fi ede ewi gbe e jade
iii. Ka koko inu ewi naa jade
 Idanrawo Fun idali Såå Iori Ede, Äsa
åti Litfrésö
Ni òpin idanilekoo akékò yòo Ie;
i. Dåhun ibeere abé ékö nåå pelü atunse ti o ye
8EdeApeko ni ede YorubaNi òpin idanilekoo akékò yòo Ie;
i. Gbo oro ti a pe jåde
ii. Ko oro ti wan gbo sile pelu ede to jinna
iii. Se atunse lori asise ti won ba se
AsaOjuse Ebi ni ile YorubåNi òpin idanilekoo akékò yòo Ie;
i. Sälåyé ojuse åbüro si égbon
ii. So iwulo tabi pataki egbon si aburo tabi aburo si egbon
iii. So ni soki bi okun ibi to so won papo se gbode le to
LitOrin kiko Iori iwaNi òpin idanilekoo akékò yòo Ie;
i. Ko orin to koni ni iwå.
B.A:- kini n o fi ole se laye timo wa
ii. gbe orin naa jade gege bi eko
9EdeAkosoro
B.A:- Yi ese re pade si apakan ja itanna itanna
to n tan

Ni òpin idanilekoo akékò yòo Ie;
i. Ko akosoro lori awon koko oro won yi
B.A:- Yi ese re pada si apakan
ii. Pe awon iro inu re ketekete
iii. Fa awon koko oro inu re jade
AsaOge siseNi òpin idanilekoo akékò yòo Ie;
i. Salåyé ni soki ohun ti oge sise ge ni ile Yoruba
ii. Daruko orisirisi ona ti a le gbå se 0ge ni ile Yorübå,
iii. salaye pätaki Oge sise ni ilé Yoruba
LiterasoOrin Kiko
BA:- Ori ewe ma paya awa lékun
Ni òpin idanilekoo akékò yòo Ie;
i. Ko orin pelu idunnu
ii. Lo ohun didun lati ko orin naa
iii. Fa koko inu orin na jade
10EdeDidåruko Eyå araNi òpin idanilekoo akékò yòo Ie;
i. Dåruko awon éyå ara ni ököokan
ii. Ya äwörån ti yoö fi eya ara kökan han
AsaOba Alådé ni ile YorubaNi òpin idanilekoo akékò yòo Ie;
i. Dåruko Oba Alådé kookan ni ilé Yorubå
ii. So. äwon ilu ti won dåde si
iii. Ko äwon oruko koökan ti wan då jåde.
LitAröSo Lori EyeNi òpin idanilekoo akékò yòo Ie;
i. Dåruko oniruuru eye ti won mo
ii. So oro nipa eye, ti won daruko
B.A:- Eye Aså- éyi nåa rikårika
iii.Ya äworån dié nipa won.
11Agbeyewö ise Såa Keta Lori Edé,
Asa ati Literaso
Ni òpin idanilekoo akékò yòo Ie;
Dáhun lbéérë abe ëké lóri édë asa ati Lítírésô
12Idånrawö Fun SåäketaIdånrawö Fun Såä keji

 

Recommended Yoruba Textbooks for Primary 1

Recommended Textbooks for Pupils & Educators

Main Text

 1. Yinka Folorunso et al, Yoruba Alakobere, WAPB, 2015.
 2. Bayo Aderanti, Ipile Eko Ede Yoruba, Nelson, 2015 .
 3.  Dotun K. O Akindele, Yoruba, Unique, 2016.
 4.  s.M. Raji et al , Fun Ile eko Alakobere, Extension, 2016.
 5. Williams O. Fatogun, Taiwo Ati Kehinde, IJniversity Press, 2014.                                                                                                                 
 6. Ayoade A. Okedokun, Omo Elede, Ayo Okedokun and Associate,2017.
 7. Oluwabukola Boripenle, Ede Yoruba Ponbele, Foursquare press, 2017.
 8. Akinwumi Atanda , lwe Kiko Ede Yoruba Alakoye, Laroked, 2014.
 9. Ola M. Ajuwon, Tanus Akotun Ede Yoruba, Tanus, 2014.

Workbook

 1. Bayo Aderanti,   Ipile Eko Ede Yoruba Workbook, Nelson, 2015.
 2.  Olu Owolabi et al,  Yoruba Ode Oni Workbook, Evans, 2015.
 3. A.l. Alimi et al, Akotun Yoruba Workbook, Melrose, 2012.                            

Handwriting

 1. Babatunde Tijani, Learn How to Read and Write(lwe Mo-on.ko Mo-on-ka), Aqua Green, 2013.
 2. Abimbola, The Yoruba Language Class (Read, write and Understand), Amsmart Consulting, 2016.
 3. Babatunde, The Yoruba Numerals(Hand writing book) Aqua Green, 2012.

Comprehension and Grammer

 1. J.F Odunjo, Comprehension Alawiye, Learn Africa, 2016.
 2. Akin Dahunsi, ABD Fun Alakobere(lwe-kin-in-ni), Oburo Bk Publisher, 2016.
 3. Babatunde Tijani, Alufabeti ABD (lwe Kika) Yoruba, AQUA Green, 2013.
 4. Olusola Fadiya, Yoruba Atomosona, Feathers & Caps, 2013.
 5. A.l. Alimi, Akotun Yoruba, Melrose, 2012.
 6. J.A. Akinniyi, Fitila Imo Yoruba, Bitmap, 2012.

Library and Use

 1. Abimbola, The Yoruba Language Class, Armsmart Consulting, 2016.

Other Categories

primary-4-scheme-of-work

Primary 4 Scheme of Work

primary-6-scheme-of-work

Primary 6 Scheme of Work

Welcome to Syllabus.ng. We’re on a mission to empower learners of all ages and backgrounds with educational resources they need to succeed academically and professionally

Professional Certification

CIBN Syllabus

CITN Syllabus

CIPM Syllabus

APCON Syllabus

Company

Career

Media Kit

Contact

© 2024 Created with Page 5 Digital
Download Syllabus