Primary 6 Yoruba Language Scheme of Work

Download the Lagos State Unified Scheme of Work for Primary 6 Yoruba Language to serve as a guide for educators and primary school teachers.

Home » Primary 6 Scheme of Work » Primary 6 Yoruba Scheme of Work

About Yoruba Language Scheme of Work for Primary 6

Primary 6 Yoruba scheme of work aims to improve the pupil’s understanding and fluency in spoken and written Yoruba. It fosters fluency, literacy, and effective communication and appreciation of the Yoruba language. It prepares the pupils to confidently engage with Yoruba culture and tradition.

The scheme for this class covers various topics such as greetings, reading a government-approved book, nouns, storytelling, writing essays, playing Ayo and Okoto games, summaries, traditional attire, Yoruba celebration songs, verbs in Yoruba language, names of kings and their towns, proverbs and their origin, listening to talking drum etc.

In conclusion, the Yoruba scheme of work for Primary 6 aims to provide the pupils with a comprehensive understanding of Yoruba language, culture, and literature. By completing these lessons, the pupils will be well-prepared for the upcoming tests and exams.

Download Primary 6 Yoruba Scheme Scheme of Work

Know what’s expected of you as an educator

Download the Lagos State Unified Scheme of Work for Primary 6 Yoruba

Primary 6 First Term Scheme of Work for Yoruba Language

LAGOS STATE GOVERNMENT MINISTRY OF EDUCATION UNIFIED SCHEME
OF WORK FOR PRIMARY SCHOOLS
Yoruba Scheme of Work for Primary/Basic 6
 CLASSPrimary/Basic 6
 SUBJECTYoruba
 TERMFirst Term
WEEKTOPICSLearning Objectives
1Idanw0 Ranpe fun ibö såå tuntun
ati åtünyewo eko lori Édé, Äså ati
Litiréso
Ni opin danilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. dåhün si åwon Ibeere to jeyo ninu lori Édé, Äså
åti Litirésö
ii. Won yoö mu’ gbogbo awon eko ti won ti kö ni
såå ti d kojå wå si irånti.
2EdeOnka Yoruba:
150-200 (Äadajö Igba).
Ni opin danilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Ka onkå Yorüba’ ni nombå åti édé.
ii, Ko donkå Yorübå ni nomba ati édé.
iii. Se åropö, isodipupo åti iyoküro ilana ede
Yorubå.
iv. Kiko åwon onkå wonyi sile pelu ise sise
AsaIkini ni ile YorubåNi opin danilekoo, åwon akéköö yoo le sålåyé:
i. ki ni ikini.
ii. Bi a se n kini fün orisirisi igbå åti åsiko.
iii. Idi ti ikini se se påtåki.
LitKika iwé ti ijoba yanNi opin danilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Daruko onköwé
ii. ka iwe naa aka dän moran.
iii. salaye Itan naå ni soki.
iv. So koko ini iwé
3EdeOro orüko, didå öro oruko mo ninu
gbolohun.
Ni opin danilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Fün örö oruko ni oriki
ii. Dåruko orisirisi oruko ti o wå.
iii. Sålåyé ise ti orö oruko n se ninu gbolohun
(oluwa,abo.eyån).
iv. Se åkojo åpeere lorisirisi.
v. Dahùn ìbéèrè Iori eko yìi
AsaÌwà Omolüàbi ni ilè YorùbâNi opin danilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Sàlàyé ohun ti ìwà omoluàbi jë
ii. So ìdi ti Yorùba fi ka omolüàbi si püpo.
iii. Daruko orisirisi ìwà omoluàbi lawujo Yoruba
iv. So tan ni Yorùba n pè omoluabi
v. Dahun Ibeere Iori eko yii
LitAlo pipa
Pipa alo apamo
Ni opin danilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Salaye ki ni alo
ii. Daruko orisirisi àlo towà
iii. Pa alo orisirisii
iv. So ìwulo alo
4EdeAroko Iori ilé ìwé miNi opin danilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Ko àròko to gbámúsé Iórí ilé iwé
ii. Sàlàyé iró àroko wo ní ilé lwé mi
iii. Dá iyato tó wà laarin àrôko asapejuwe àti orísi
àrôko yókü
iv. Se àlàyé Ióri bí a se ko êro lori iru àrôko yi.
AsaAyô tita àti okoto titaNi opin danilekoo, åwon akéköö yoo le:
i, Daruko iró eré won; ayô tita àti okoto tita.
ii. Sàlàyé bi a se n ta awon ere wonyi.
iii. So iye àwon tó le se ere
iv. Jiroro nipa ôfin ere
v. Dárúko ohun êlô fún awon ere wonyi
Litlwé Kikà ijoba yan.Ni opin danilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. So nipa ônkówé
ii. Salàyé itàn náà ni sókí
iii, ka naà ni àka dán moran,
iv, Wá ‘itumo si àwon oro tuntun tó súyo ninú ibi
kikà náà.
v. so koko ti itan naà dálé,
5EdeÄkåyéNi opin danilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Sålåye ki ni akaye
ii. Dåruko orisirisi åkåyo to wå mo olorö wuuru,
oni ewi åti oni itåkuroso.
iii. Salaye ilana ti a n telé nigbå ti a bé ri ka åkåyå.
iv. So koko inu akaye naa
v. Dahun Ibeere abe åkåyé naå.
AsaOge ise ni YorubaNi opin danilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Sålåyé ki ni oge sise
ii. Daruko åwon ona kara loge.
iii. Sålåyé oköokan won pélu åpeere.
iv. So iwulo oge sise
v. Dåhün lbééré Iori eko yii
LitOrin ayeyo Yorübå bii
Orin lyåwo, Orin etiyeri
Ni opin danilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Sålåyé ki ni orin ayeye Yorübå.
ii. Då åwon orin wonyi omo
iii So patåki åwon orin
6EdeOro ise ninu ede YorubaNi opin danilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. sapajure oro ise
ii. Daruko orisirisi oro to wa ninu ede Yoruba
iii. Se ekunrere alaye lori okookan eya oro ise
iv. lo won ni gbolohun kikun
v. Da won mo ninu gbolohun
vi. So ise ti oro ise n se ninu gbolohun
AsaOruko awon Alade ati ilu wonNi opin danilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Daruko awon oba alade ati ilu won
ii. So nipa itan oba ilu kookan
iii. Ni imo lori bi awon oba se te ilu de
iv. Dahun Ibeere lori eko yii
LitItandoweNi opin danilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. So oriki itandowe
ii. Jiroro nipa awon owe onitan
iii. Salaye itan to bi owe kookan
iv. Se akojo itandowe
v. Fa eko inu itandowe yo
vi. Dahun Ibeere lori eko yii
7Idanwo idaji saa yii/ ibewo awon
obi / isinmi
Idanwo idaji saa yii/ ibewo awon
obi / isinmi
8EdeOrö eyånNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. So oriki eyån
ii. Da eyån mo ninu gbolohün
iii. Dåruko orisirisi eyån to wa ninu ede Yorübå
iv. Se amulo okookån ninu gbolohun
AsaÄsa iranra eni Iowo ni YorubåNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Sälåye ki ni åså iranra eni lowo ni ile Yoruba
ii. Dåruko åwon onå iranra eni lowo ni Yoruba’
iii. Sålåyé ököokan wen pélu åpeere.
iv. Dahun ibeere lori eko
LitGbigbö ohun ti a fi ilü wiNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Da orisirisi ilu Yorüba mö
ii. Sålåyé ohun ti a n lo wan fün
iii. Såpéjuwe bi Yoruba se n fi Ilu soro
iv. Dahun beere lori eko
9EdeÖrö Aropo oruko ninü édé YorübåNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. So oriki aropö oruko
ii. Da aröpo oruko mo ninu gbolohun
iii. Daruko aropo oruko orisirisi to wa ninu ede
Yoruba
iv. Se amulo okookan ninu gbolohun
AsaIla kiko ni ile YorubaNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Salaye ki ni llå kiko
ii. Dårüko orisisi ilå to wa låwüjo
iii. Jiroro nipa ökoökan won.
iv. Salaye a ‘kobå ti oIajü se fun å ilå kiko
v. Dahun Ibeere Iori eko yii
LitIgbågbö åwon Yorüba’ nipa
Olodumaré
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. So oriki 0lodumare
ii. Jiroro nipa Igbågbo åwon Yorübå nipa
Olodumare
iii. Dårüko åwon oruko miiran ti Yorubå n pe
olodumaré åti iltumo won
iv. Dåhün ibééré lori
10EdeÂkànlò èdè iti ìtumo wonNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. So orisi orikì àkànlo òdè
ii. Daruko àwon Âkànlò édè
iii. Dahûn ìbéèrê lori eko
iv. L0 won ni gbolohun kikün
AsaÂsà Isinkü ni ile YorubaNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Sàlàyé ki ni àsà lsìnku ni ilè Yorûba’
ii. Jiròrò nipa ohun ti a n l0 adie irànà fun
iii. Sàlàyé bi a se n toju oku ati òku’ sinsin
iv. Dahun Ibeere Iori eko
LitIwe kika ti Ijoba yanNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. So nipa onköwé
ii. itån nåå ni soki
iii. ka iwé naa ni åkå dån morån,
iv. Wo ltumo si åwon oro tuntun to suyo ninu ibi
kikå naå.
v. So koko ti Itan naa dålé.
11EdeOro AponléNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Salaye kl ni oro åpönlé?
ii. Da ise ti öro åpönle se ninu gbolohün mö.
iii. Toka si åpönle ninu gbolohün
iv. dåhun Ibeere Iori eko
Asaoriki åbiso nile Yorubå åti idilé.Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Ki 0riki oruko åbiso
ii. Se åpeere oruko åbiso
iii. Dåruko åså åti ise to rö mé oruko åbiso
iv. jlroro nipa påtåki oruko åbiso
LitEré OsupaNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. So itumo ere osupa
ii. Dåruko orisirisi ere osupa
ii. Såpejuwe bi a ti se åwon ere wönyi
iv. Jiroro nipa ofin to dé eré kookan
v. dåhün ibeere Iori eko
12EdeLétå Gbefé ati aibefeNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Salaye Isori letå ti o wa
ii. Såpéjuwe ilana ti a fi n ko létå nåå
iii. Toka si awon ori örö Iåbé leta kookan.
iv. Dahun Ibeere to jeyo.
iv. dåhün Ibeere lori eko yii
AsaOye jijeNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Salaye itumo oyé jije
ii. So nipa bi a se n joyé nile Yorübå
iii. Toka Si orisisi oyé ti an je
iv. Jiroro nipa awon Ohun élo oye jije
v, dåhün ibééré Iori eko yii
Litlwé Kikå – Itan Ijåpa’ ati omo
Alåkårå.
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Salaye itan ijåpå ati omo Alåkårå.
ii.Dåruko awon eda inu itån yii.
iii. So iru eranko ti Ijåpå jé.
iv. Jiröro nipa åwon koko t o jeyo
v. dåhun Ibeere lori eko yii
13Atunyewo eko lori ise saå yi ninu
Édé, Äså åti litereso
Atunyewo eko lori ise saå yi ninu
Édé, Äså åti litereso
14Idänwo saå kiini 

Primary 6 Second Term Scheme of Work for Yoruba Language

   
 CLASSPrimary/Basic 6
 SUBJECTYoruba
 TERMSecond Term
WEEKTOPICSLearning Objectives
1Idånwo Ranpé fun ibere såä
tuntun
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
– mu gbogbo åwon ti won ti kö ni såå ti o kojå wa
si irånti.
2EdeÉdé:Itesiwaju Eko ninu onkå
Yorubå 200-250
(igba – Ötålugba-din- lügba)
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Ka onkå Yorubå ni nomba ati ni edé Yorubå
ii. ko onka Yorübå ni nomba ati ni edé Yorüba’
iii. Se åropo,iyokuro åti isodipupo ni Ilana edé
Yorübå
iv. dahun Ibeere Iori ekö
AsaIgbéyåwo nile YorubåNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Sålåyé ki ni åså igbeyåwo?
ii. Dårüko orisirisii igbéyawö to wå ati bi a fe ri
sewön.
iii. Ilana ati igbése inu igbéyåwo. Bi apeere
Ifojusade,iwådii, Alårinå, Isihén,itoro idåna abbl.
iv. Dåruko åwon ohun elo Idana
v. Sålåyé pataki ki oko gba ipale iyawo re.
vi. dåhun ibeéré Iori eko
LitItan awon Akoni Yorubå.
i. Efunsetun Aniwürå
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Sålåyé ta ni akoni?
ii. Såpejuwe awon akoni wonyi.
iii. Da ise/nnkan ti wön tå so won di akoni.
– dåhün Ibeere lori
3EdeAroko Asånyanjiyån.
(Ile iwe ijoba dåra ju ilé iwé
aladani lo)
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Ko årokö to månå doko Iori ori örö ilé iwe ijoba
dara ju ile iwé aladani lo
ii. Sålåye Ilana ti a se n kö åroko asåri yån jiyan.
iii. Då åwon ori örö ti a lå bå pådé ireifé årdko yii.
– dåhün ibééré lori
AsaEko ile ni ile YorubaNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Fun eko ile ni oriki to koju osun won
ii. Daruko orisirisi eko ile towa
iii. Salaye okookan awon eko ile wonyi
iv. Da idi ti Yoruba se n ko awon omo eko ile mo
v. Dahun ibeere lori eko yii
LitAkanlo ede ati itumo wonNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Fun akanlo ede ni oriki
ii. Se akoojo apeere akanlo ede ati itumo won
iii. Lo awon akanlo ede wonyi ni gbolohun
iv. Salaye iwulo akanlo ede
v. Dahun ibeere lori eko yii
4EdeOro ati idakeji reNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Se akojo awon oro Yoruba lokan-o-jokan
ii. Wa idakeji si awon oro won yi
iii. Lo awon oro wonyi ni gbolohun kikun
iv. Se akosile koko idanileko sinu iwe won
v. Dahun ibeere lori eko yii
AsaAkojopo awon owe ile YorubaNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. salaye kinni owe je
ii. Daruko isowi owe
iii. Se akojo oniruuru owe
iv. Toka si iwuko owe-ilo, owe-ibawi, imooran,
ikilo, alaye, abbi
v. So iyato laarin awon owe won yii
vi. Dahun ibeere lori eko won yi
LitEre OniseNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Fun ere onise ni oriki
ii. Ya aworan ere onise sokan
iii. Se ore onise laarin ara won Iori ìtàgé
iv. dàhùn ìbéèrò Iori eko yii
5EdeAmi ohùn ninü òdè YorùbàNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Daruko àmì ohùn to wa ninü ède Yoruba
ii. Sàlàyé iwulò àwon àmi ohùn yi
iii. Sàpèjuwe awon àmì ti a n lo fun àmì ohûn
kòkan
iv. fi ami si on oro Yorùba’
v. Sàlàyé pataki ami ohùn ninu ede Yorùba
iv. dahun Ibeere lori eko yìi
AsaOrüko AmutorunwaNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Sàlayé ki ni orüko àmutorunwa pelü apeere.
ii.Dâruko orisirisii oruko àmutorunwa
iii. Sàlayé òkookan awon oruko wönyi
iv. dåhün lbéere lori eko yii
Litiwe kika-Olooro Geere/Wuuru
Awon asa to suyo ninu asayan iwe
ti ijoba fowo si
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Fa åwon åså to suyo ninü iwé naa yo
ii. Se ékünréré ålåyé Iori åwon åsa naå
iii. Sålåyé koko ti itån nåå da le lori
iv. dahün ‘Ibeere lori eko
6EdeOro aponle ninu ede YorübaNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Fun oro aponlé ni oriki kikun
ii. Se åkojo orisirisi oro åponlé ninu gbolohün éde
Yorüba
iii. Sålåyé ise ti öro aponlé ri ninü gbolohün
iv. dåhün ibeere lori eko yii
AsaIse abinibi ni ile waNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Sàlàyé àwon ìsori ise abinibi ni Yorùbâ
ii. Daruko àwon ise abinibi ile Yorùba
iii. Juwe bi a se n’ se àwon ise wonyi
iv. Jiròrò nipa àwon ohun èlò ise kookan
v. Dahun Ibeere Iori eko
LitFifa ewà èdè inu iwé kikà yoNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. fun ewà èdè/ onà èdè ni orikì kikün
ii. Fifa àwon ewà èdè wonyi yo àti ìtunmo.
Apeere – ôwe, awitunwi, àkànlò-èdè, àfiwé,
ìfohunpènìyàn
iii. Alaye kikun lori àwon ewà èdè wonyi
iv. Dahùn ibéèrê Iori èkô
7Idanwo Saa Keji
Ibewo àwon òbi
Ìsinmi ìdajì saa keji
Idanwo Saa Keji
Ibewo àwon òbi
Ìsinmi ìdajì saa keji
8Edeltesiwåju eko Iori Äroko Asåriyån
jiyån.
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Ko åroko to boju mu.
ii. Da åwon ori orö ti a Io påde låbe irüifé åroko yii.
iii.Se åmulo åwon ilånå ilåpa oro fun kiko åroko yi
iv. dåhun si ibéére Iori eko yi
AsaOjuse obi låwujo ati ninu ileNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Sålåyé tani obi
ii. Menu ba isé obi lara omo, Iawüjo ati Iåårin
iii.Bééré lbééré Iori ohun ko yé won to.
iv. dahun Ibeere Iori yii
LitIwé kikå ti ijoba fowo si.Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Då ka iwé literaso yii ni åkågbåddn.
ii. Fün åwon öro itumo won farasin yo.
iii. Salaye ekå ti a ri
iv. dåhün ibéeré lori eko yii
9Edetuntun yo ninu łwe âkâyĆ ati itumęNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Sâkojo âwon oro tuntun to șuyę
ii.Wa itumo si âwon wonyi.
iii.Se âmulo won ni gbolohun kikun.
iv. dahun Ibeere Iori ëko yii
AsaOna iranra-ęni-lowo
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Salaye onâ igbaranra-eni-lowo
ii. Daruko âwon ona îranra-ęni-lowo nilë Yorubă
iii. Mënuba îwulô âti pataki łranra-ęni-lôwo lăwujo
iv. dahun Ibeere Iori eko yii
LitÂwon ounję abinîbi ilę Yoruba
isu egbe, élübo, ewebe, abbl.
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. dăruko orișisi ounję ilę wa
ii. Salaye kikun lori bi a ti ri se ounję kookan
iii. jiroro nipa lwulo ati påtåki Ounje
iv. dåhün ibéere Iori eko
10EdeGbolohün édé Yorübå.
-Gbolohun eleyo oro ise
-Gbolohun oIöpö örö ise.
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Fin gbolohün ni oriki kikün.
ii. Då orisirisi gbolohün mo
iii. Sålåyé gbolohun eleyo örö ise ati olopö oro ise.
Pelu apeere.
iv. salaye abuda åwon gbolohün wönyi ati Iyato
åårin won.
v. dåhun ibeere lori eko yii
Asalsedå åti itånkåle omo Yorübå.


Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Sålåyé bi åwon Yorubå se se
ii. Mo orirün won åti iran won ti se
iii. Menuba bi won tan kåle
iv. Dahun ibeere abe eko
LitEwi atinudaNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Fun ewi ni oriki kikun
ii. Ronu jinle lati ko ewi
iii. Mo eroja ewi
iv. Salaye ilana ewi
v. Kewi fun ra won
vi. Dahun ibeere lori eko yii
11EdeOro ApejuweNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Fun oro apejuwe ni oriki kikun
ii. Salaye oro apejuwe
iii. Lo oro a[ejuwe ni gbolohun
iv. Dahun ibeere lori eko yii
AsaAgbara ede Yoruba
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Salaye kinun lori agbara ede Yoruba
ii. Daruko awon ohun ti a n lo ede Yoruba fun.
Apeere-Aduragbigba, iwure, eebu bibu, ati epe sise
iii. Soro lori pataki ede lawujo
iv. Dahun ibeere lori eko yii
LitIse sise (ki ma se ìmélë).Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Sàlàyé pàtàkì ise
ii. Mënu ba ìhà ti Yorûbâ ko si ìmele.
iii. Sàlàyé àtubotân ise sise àti ìmëlë sise
iv. déhùn ìbéèrè Iori èkô yìi
12EdeÈyan oro ninu gbolohùn.Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Fun oro eyân ni orikì kikân.
ii. Sàpèjuwe òrò èyan.
iii. Fala si oro eyan ninu gbolohun.
iv. Mo isë ti oro n ninu gbolohùn.
v. dahun Ibeere lori eko
AsaÀnfaàni àti alebu ise ajumoseNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Sàlàyé ohun ti isé ajumòse je.
ii. Dàrüko orisirisii ise ajumose laarin Yorüba
iii. Sàlàyé ànfààni to wà ninu ise ajumose,
iv. Dårüko åwon ålébü ise åjumose,
v. dåhun Ibeere lori eko
LitKika iwé Itan aroso ti Ijoba yån
pelu ekö ti ko ninu re
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Ka iwe kikå nåå ni gbolohun.
ii. Sapéjuwe aworan edå itan.
iii. Sålåyé koko ise ti onkowe n se ni awujo waa.
iv. Sålåyé åså Yorübå to suyo
v. dåhün lbéere Iori eko
13Atunyewo eko Iori ise saa yii ninu
Édé, Äså ati litireso
Atunyewo eko Iori ise saa yii ninu
Édé, Äså ati litireso
14Idanwo saa kejiIdanwo saa keji

Primary 6 Third Term Scheme of Work for Yoruba Language

   
 CLASSPrimary/Basic 6
 SUBJECTYoruba
 TERMThird Term
WEEKTOPICSLearning Objectives
1Idanwo Ranpe fun såå tuntunNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
-mu gbogbo åwon eko ti won ti kö ni saa ti o koja
wå si Iranti.
2EdeOnka YorubaNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Salaye bi a se lé se aropo onka Yorübå
ii. sayokuro onka
iii. ménuba påtåki
iv. dåhün ibééré lori eko yii
AsaOge sise laarin okunrin laye atijoNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Salaye kini oge sise
ii. Sapejuwe oge sise awon okunrin laye atijo
iii. Daruko orisirisi ona ti awon okunrin n gba se
oge laye atijo
iv. Menu ba iyato to ti de baa laye ode oni
v. dahun ibeere lori eko yi
LitSisa åwon oro titun yo ninü iwé
kikå Ijoba fowosi
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Ka we naå ni åkåjé
ii. Won yoo le fun awon orö ti won ka pe daa däa
tåbi ti won ko mo itumo won yi
iii. Sälåyé åwon örö wonyi lokoökan
iv. dahun Ibeere lori eko yii
3EdeDida oro ise mo ninu gbolohunNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Sålåyé ki ni örö
ii. Da oro ise mo ninu gbolohün
iii. Sålåyé ise ti öro ise n se ninu gboldhun
iv. dåhün ibééré Iori eko
AsaAnfaani ati Åléébu to wa ninu eré
Idaraya
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Sålåyé ohun ti eré Idårayå je
ii. Dåruko orisirisi eré Idårayå ati bi a se see
iii. Salaye anfaani ati aleebu awon ere wonyi
iv. dahun Ibeere lori eko yii
LitItan siso ati fifa åwon owe yo ninu
itån nåå
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Wå orisirisi ltån alådün låti so
ii. Fa owe inu åwon ltån kookan yo pelu eko to n
kowa
iii. Salaye awon owe wonyi
iv. dåhün ibééré lori eko yii
4EdeSllébu Édé Yorubå pinpin oro si
silebu
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. tun silebu ni oriki
ii. sâlâyó orisi silebu to wa
iii. pin oro si silebu
iv. dahun Ibeere lori eko
Asałdana ni ile Yoruba ati awon eroja
îdaana bii – oyin, atare, Óbi, ișu,
owo, orogbo, așo, apoti așo.
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. salaye nipa așa idana
ii. dăruko âwon ohun elo Idana
iii. sâlâye bi a șe n fi okookan won sadura
iv. męnu ba pâtâki łdana ati âwon ohun elo ‘Idâna
v. dăhun Ibeere lori eko
LitÂgbeyewo âwon itân wuru pęlu
âtupalę
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. da ltan wuuru mo gegebi okan lara arisa åkåyé
ii. ka orisirisi ltån wuru ni åkå gbådün
iii. salåyé llånå ti a måa ri låti dåhün åkåyé onitån
wuuru
iv. åkåyé onitån wuru
v. dåhun ibééré Iori eko
5EdeÄtunyö ewo awon isori girama
Apeere
-örö oruko
-örö Ise
-örö Aropo
-OrukQ
-oro eyån
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. sålåyé åwon isori giråmå wönyi – oro oruko,
oro ise, åti öro aropo oruko
ii. se åpeere orisirisi åwon Isori girama wonyi
iii. då won mo ninu gbolohün
iv. Io won ni gbolohün kikun
v. dahun Ibeere Iori eko
AsaÄgbéyewo isedale ati itankale äti
åwon omo Yorubå
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Jiroro nipa imo åteyinwa
ii. Sålåyé Iori isedale äti iatnkale omo Yoruba
iii. Soro Iori ibi ti iran Yorubå ti åti ibi ti won tan
kå dé
iv.Da åwon ati eyå Yorubå mö.
v. Ménuba iyåtö tö wä låårin eka’eyå Yorubå an si
ikeji.
LitAwon ounje abinibi ile YorubaNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Daruko awon ounje abinibi ile yoruba
ii. Sapejuwe bi a tin se okookan ounje wonyi
iii. Salaye pataki awon ounje wonyi
iv. Dahun ibeere lori eko yii
6EdeAgbeyewo Iori konsonåti YorübaNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Fun Iro ede ni oriki kikün
ii. Dåruko orisirisi ro ede ti owa
iii. Ka iro fåwefi åti konsonånti
iv. Lo iro mejeeji låti pe örö fide
v. dåhün ibeere Iori
AsaÄgbéyéwo Eré Idårayå:
Älö Äpamö iti Äpagbe
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Sålåyé itumö alo
ii. Menuba isori ålö
iii. Jiroro nipa iwulo alo
iv. Dahun Ibeere lori eko yii.
LitÄgbéyéwo åwon itån wuru pelu
itunpale
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. da itån wuuru mo gégé bi okan léra årisa åkåyé
ii. ka orisirisi itån wuru ni åkå gbådün
iii. salaye Ilana ti a måa n tele lati dåhün åkåyé
onitån wuuru
iv. åkåye’ onitån wuru
v. dåhün lbeere Iori eko yii
7Idanwo Saa keta
Ibewo åwon obi
Isinmi idaji såå keta
Idanwo Saa keta
Ibewo åwon obi
Isinmi idaji såå keta
8EdeAgbeyewo iro ohun
Ohun oke
Ohun isale
Ohun alaarin
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Salaye ni kikun itumo iro ohun
ii. Daruko orisirisi iro ohun ti owa ninu ede
Yoruba
iii. Da awon ami ohun to wa lori oro pe
iv. Fi awon ami to ye sori oro kookan
v. Salaye pataki ati iwulo ami ohun
AsaOruko awon oba AladeNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Daruko awon oba alade ile Yoruba ati ilu ti won
tedo si
ii. Se apejuwe okookan awon oba wonyi
iii. Daruko oruko oye oba ilu kookan B.a,
Ooni ti Ile Ife, Alaafin to ilu Oyo, abbi
iv. Dahun ibeere lori eko yii
LitAgbeyewo awon owe onitanNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Salaye itumo owe onitan
ii. Toka si awon owe onitan
iii. Menuba iwulo åwon owe onitån
iv. Dåhün ibéere Iori eko
9EdeAtunyewo oro eya ninu gbolohun
ede Yoruba
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Fa örö eyån yo ninu gbolohun
ii. Salåyé ise ti oro eyan n se ninu gbolohun
iii. Lo oro eyån ninü gbolohün ni kikån
iv. Dahun Ibeere to jeyo ni abala yi.
AsaAsa araraenilowoNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Sålåyé itumo åså Iranraenilowo
ii. Dåruko orisi asa iraraenilowo
iii. Ménuba iwulo åti pataki aså Iranraenilowo
iv. Dahun Ibeere Iori eko yii.
LitAgbeyewo awon ewi alohun to wå
fun ayeye nile Yorubå
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Fun ewi alohün ni Oriki
ii. Sålåyé åbudå ewi alohun
iii. Dâruko orisii ewì alohùn laàrin àwon Yorûbi
b.a. lyèrè Ifa, Orikì Orilè, Sàngo pipè, abbi.
10EdeÂtunyèwo èkô Ior oro aponle ati
oro atokan
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Jiroro nipa oro aponle ati oro atokun
ii. Se kikun nipa iwa omoluabi
iii. Se apejuwe oro aponle ati oro atokun
AsaÂtunyèwo èkô Iori iwa omoluabi ati
ojuse eni gege bi obi ati olori ilu
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Jiròrò nipa ìmo àleyinwa’
ii. Sàlàyé kikün nipa iwà omolüàbi
iii. toka si ojuse òbi Iori omo àti ojüse olori ilu
LitÂgbéyewo àwon orin ayeye
ìgbéyàwo àti isomoloruko
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Se àkojo àwon orin ayeye Ìgbéyàwo
ii. Se åkojo åwon orin isomoloruko
iii. Ménuba påtåki awon orin wonyi
iv. Dåhun Ibeere Iori eko
11EdeAtunyewo eko lori leta kikoNi opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Rånti imö åteyinwa lori eko yii
ii. Sålåyé orisii leta to wa
iii. Soro nipa Ilana leta kökan
iv. Såpéjuwe bi a n ko leta kookan
v. Dahün ibééré ni abala ‘ekö yii.
AsaÄtünyewd orüko nile Yorübå.
Orüko åbiso, amutorunwå åti
Inagije
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Se alaye kikun lori oruko kookan
ii. Se åkojo åwon orüko köökan gege åpeere
iii. Se iyåtö låarin orüko wonyi
iv. ménuba påtåki Idi ti Yorübå fi je oruko naa
v. Dahun awon ibeere tö jeyo
LitÄtånyéwo eko lori awon eda itån
ninu litereso ti ijoba yån
Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le:
i. Jirorö nipa imö ateyinwå
ii. Daruko åwon eda itan kookan
iii. Sålåyé ipa ti ököökan ko
iv. Dahun Ibeere ti o jeyo.
12Atunyewo eko Iori ise saå yii ninü
Édé, Äså åti litirésö
Atunyewo eko Iori ise saå yii ninü
Édé, Äså åti litirésö
13Idanwo saa KetaIdanwo saa Keta

Professional Certification

CIBN Syllabus

CITN Syllabus

APCON Syllabus

Company

Career

Media Kit

SyllabusNG

© 2024 Created with Page 5 Digital
Download Syllabus