Primary 5 Yoruba Language Scheme of Work

Download the Lagos State Unified Scheme of Work for Primary 5 Yoruba Language to serve as a guide for educators and primary school teachers.

Home » Primary 5 Scheme of Work » Primary 5 Yoruba Scheme of Work

About Yoruba Language Scheme of Work for Primary 5

Yoruba language is taught in primary school to make the pupils understand their mother tongue. Teaching Yoruba in Primary school helps to preserve the cultural heritage and instill a sense of identity in the pupils. 

In this class, the pupils would be taught poems, Yoruba numbers, naming ceremonies, Yoruba literature, pronunciation of vowels, traditional clothing in ancient times, Yoruba proverbs, comparative words, lineage marking, idioms and meanings, moonlight games, folktales, fashion in Yoruba land, reciting poems and extracting morals, and descriptive writing etc.

The educator should ensure that the pupils are taught in Yoruba and they should be encouraged to communicate in Yoruba too. This will enhance the understanding of what is being taught.

Download Primary 5 Yoruba Scheme of Work

Know what’s expected of you as an educator

Download the Lagos State Unified Scheme of Work for Primary 5 Yoruba

Primary 5 First Term Scheme of Work for Yoruba Language

LAGOS STATE GOVERNMENT MINISTRY OF EDUCATION UNIFIED SCHEME OF WORK FOR PRIMARY SCHOOLS
Yoruba Scheme of Work for Primary/Basic 5
 CLASSPrimary/Basic 5
 SUBJECTYoruba
 TERMFirst Term
WEEKTOPICSLearning Objectives
1Idanwo Ranpe fun saå tuntun.
Édé/Äså/Litireso
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. mu gbogbo åwon eko ti won ti ko ni saå ti o
kojå wå si irånti.
2Edeönå lbénisoro ni ayeNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Fun ona Ibanisoro ni oriki
ii. Déruko orisirisi ona Ibanisoro ni aye atijo.
iii. Salaye awon ona Ibanisoro wonyii
v. Dåhun Ibeere 1ori yii
AsaOmoluabiNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i, Fun iwå omolüåbi ni oriki
ii. Dårüko orisirisi Iwa to fi mo iwa omoluabi
iii. Se eré to se åfihån omoluabi
iv. dåhün ibedee Iori eko yi
LitKikå ewi apiIeko lori oriki llu Osogbo.Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Ki oriki osogbo la ka gbådün.
ii. Sålåyé pataki oriki naa
iii. dahun Ibeere Iori oriki yii
3EdeOnka Yoruba
Édé: 100-130 abbl.
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Ka onkå Yorübå ni nombå ati édé,
ii. Ko onka Yoruba ni nombå åti éde.
iii. Se aropo, Lodipupo ati iyokuro ni Ilana ede
Yorubå.
iv. Kiko awon onka wonyi sile pelü ise sise.
AsaOhun Elo IsomolorukoNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Dåruko orisirisi elo isomoloruko
ii. Sise ålaye lon iwulo won
LitLiteraso Ile YorubaNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Fün Iitireso Yorübå ni oriki
ii. Dåruko orisirisi eya litirésö Yorübå pin si
iv. dahun Ibeere Iori eko yii
4EdeKiko Iro faweli ni éde YorubéNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Fün fawefi édé Yorübå ni oriki
ii. Daruko orisirisi faweli ti o wa
iii. Sise alåyé påtåki Iori Iro fawafi alranmupé
åti aranmupe pelü apeere
iv. Dähun beere Iori eko yii
AsaAso wiwo ni aye itijo ni YonibåNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Fun aso wiwo ayé åtijö edé Yorüba ni orikl
ii. Daruko orisirisi aso wiwö ti o wa
iii. Sise ålåyé påtåki lori aso wiwo ni ile Yorüba
iv. Dahün ibeére Iori eko yii
LitOwe nile YorübåNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Fun owe nile Yoruba ni oriki
ii. Daruko orisirisi owe ti o wa
iii. Sise ålaye lori wulo won
iv. dahun ibééré Iori eko yii
5EdeOro ÄfiwéNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i.. Fun Qro afiwé ni Oriki
ii. Dåruko orisirisi oro afiwé to wa ninu ede
yoruba
iii. Se ekunroro ålaye lori okookan eya oro
iv. L0 won ni gbolohun kikün
v. Da won mo ninu gb0lohûn
vi. Sadé rewà pupo bii eye okin

Asallà kiko ni ilè YorubâNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Sàlàyé ki ni llà kiko
ii. Dâruko orisisi ilà to wa lawujo
iii. Sàlàyé ëkòkan won.
iv. Salaye a koba ti oIajü se fun é ilà kiko
v. Déhùn ìbeere lori ekô yìi
LitÌwé kikà ti ìjoba yanNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. So nipa òrikòwe
ii. Salayé ‘itàn naa ni soki
iii. ka ìwe naa ni àka dan moran.
iv. wa ìtumi si àwon oro tuntun té suyo ninü ibi
kika naa.
v. So koko ti Itan naa dalé.
6EdeAkanlo ede ati Itumo wonNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. So orisi orikì Âkànlò èdè
ii. Daruko àwon Âkànlò ède
iii. Déhùn ìbéère lori eko
iv. L0 won ni gbolohun kikün
AsaEré ÔsupaNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Salaye kini ere òsùpa
ii. Daruko orisisi ere òsùpé to wa lâwojo
iii. Sàlàyé eré òsùpa àti eré ojümô.
iv. dahûn ìbéèrè Iori ekô yii
Lititan arooNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. salaye ìtan àroso naa ni soki
ii. ka iwe naa ni akadàn moràn.
iii. wa itumo si awon oro tuntun to suyo ninu ibi
kikà naà.
7Idånwo daji saa / Ibewo åwon obi/
Isinmi
Idånwo daji saa / Ibewo åwon obi/ Isinmi
8EdeÄröko letå kiko orisisi létå to waNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Salaye ki ni leta kiko
ii. Dårüko orisisi letå to wa nile Yorubå
iii. Salaye oköökan wan
AsaOge sise ni ile YorubaNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Salaye ki ni oge sise
ii. Dårüko åwqn ona isara loge.
iii. Sålåyé ököökan won pelu åpeere.
iv. So lwülo oge
v. Dåhun Ibeere Iori ekö yii
LitEka Yoruba ati Itankåle wonNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Siso itankale åwon Yorubå
ii. Dåruko åwon ipile to je ti iran Yorubå
iii. Yiya maåpö ipinle Yorübå
9EdeÉyå ara ifoNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Säläyé ki ni eya ara ifo
ii. Daruko awon orisirisi eya ara ifo
iii. Sålåyé ököökan won pélu yiya aworan.
iv. dahun ibéere lori ‘eko yii
AsaOge sise ni ile YorubaNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Sålåyé ki ni oge sise
ii. Dårüko awon ona Isara löge.
iii. Salayé okookan won pelu åpeere.
iv. So iwülo oge sise
v. Darüko awon ohun elo ti a fin Soge yåla ni åye
atijo ati ode oni
LitOrin ayęyę Yoruba bii
orin iyawo, orin etiyęri
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Sâlâye ki ni orin ayęyę Yoruba.
ii. Da âwon orin węnyi mo
iii So patakl awon orin wonyi
iv. Sâlâye ohun ti a n Io âwon orin yii fun
10EdeÔnâ Ibănisęro ni ÔdeonNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Fun ona ibanisoro ni oriki
ii. Daruko orișiriși ona fibanisorę ni ode oni. .
iii. Sâlaye âwon ona ibanisoro wonyi
v. Dahun ibeëre lorî ëko
AsaOruko jiję nile YorubăNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Fun oruko jiję ni orikl
ii. Daruko orișiriși ona ti oruko jiję pin si b.a
Oruko amutunrunwa
– Oruko dile
– Oruko òrikì
iii. Sàlàyé àwon oruke jije wonyi
iv. dahûn ìbeere lori eko yìi
LitKikà ewì apilëko àti igbedegbe ken àti
yiyo komookun, ogbon inu ewi naa
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Ka ewi àti igbadegba kan ti olûkô yan lâyò
ii. Sàlàyé pàtàkì ewìì naa
iv. dahun Ibeere Iori ewi yìi
11EdeÂròko AgàpejuweNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
-Ki orikì àròko asapejuwe
-Sàlàyé irüfë àruko yi. Bi àpeere:
i. Ilé ìwé mi.
ii. Ore mi.
iii, Olùko ti mo feran ju
-Dihùn ìbeere Iori eko
AsaOrüko ÂmutorunwaNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
-So İtumö orüko amutorunwa
-Dârüko orüko amutorunwâ nile Yorübâ, b.a.
lgâ, Âina, Ojo,Tâiwo, Idogbo, Idoha, Idowü,
Âlâbâ, abbi.
-şâlâye Itumo tö rö mo oruko âmutorunwâ
-Dahun ibeere lori çko
LitOrin İremolekunNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. So İtumo orin Îremolekun
ii. Ko die ninü orin İremolekun. Bi apeere:
Ta lö nâ o?
çyç ni
Sokomo on ko salo.
-Dâhûn lbeere lori eko
12Atunyçwo çko lori işç lori ede, aşa ati literaso.
13Idanwo saa kin-ın-ni

Primary 5 Second Term Scheme of Work for Yoruba Language

   
 CLASSPrimary/Basic 5
 SUBJECTYoruba
 TERMSecond Term
WEEKTOPICSLearning Objectives
1Idanwo Ranpe fun ibere saa tuntunNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Rånti gbogbo imo ateyinwa lori eko yii
ii. Won yöo mo asise won ati ona atunse
2EdeÄkaye — Fifa örö to ta koko yo pelu
itumo won.
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Ka akaye ni
ii. Fa koko inu åkåyé yo
iii. Se ‘ltupale awon oro to takoko
-Dåhün ibééré lori eko
AsaIlana Igbeyawo IbileNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Salåyé ohun ti igbéyawo je?
ii. Daruko ilånå / igbése Igbéyåwo Äpeere:
Ifojusode, iwådii, alarina, isihun, abbi.
iii. Daruko åwon ohun elo idåna obi,orogbo, isu,
oyin, iyo, sugå, åådün, Ireké, abbl.
-Dahün lbéere lori eko
LitKika iwe åpileko ati gbådegbåNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Ka iwe litireso ni åkågbådun
ii. Fa koko inti iwé kikå yo
iii. Salaye eko ati ise ti we naa n ran si åwujo
iv. Dåhun lbéere lori eko
3EdeOruko osu to wa ninu odun ni ede
Yorubå
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Dårüko awon osu ninu odun
ii. Jiroro nipa påtåki osu naa
iii. Sålåyé bi a se n pe awon 0su naå ledé
Yorübå
iv. So iyato oruko 0su naa lédé Öyinbo ati
Yoruba
v. Ko orin ti so nipa awon 0su naa
vi. Dahun ibéere lori èko
AsaÂfiwé ìgbeyàwo Ibile ati tode-oniNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. So iyato laarin igbeyawo aye atijo ati ode oni
ii. Salaye ijora ati iyato laarin ugbeyawo aye atijo
ati ode oni
iii. Jiroro nipa awon ona igbeyawo won yi
iv. Dahun ibeere lori eko
LitKika iwe ere onitan keekeekeeNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Ka iwe na ni akagbadun
ii. Fa koko ninu iwe kika naa
iii. Jiroro nipa awon asa to suyo
iv. Fa akanlo-ede ati owe inu iwe kika yo
v. Salaye awon eko ti o jeyo ni bala ibi kika
vi. Dahun ibeere lori eko
4EdeOro ise keekeekee ninu gbolohun
-Apeere, de, wa, je, lo, sun, gba, pa,
abbi.
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Fa oro ise yo ninu gbolohun
ii. Salaye ise ti oro ise n se ninu gbolohun
iii. So iyato laarin oro ise keekeekee ati nla
iv. Dahun ibeere lori eko yii
AsaAlaye nipa awon ohun idana ni ile
Yoruba -Apeere, Isu obi, orogbo,
ataare, oyin abbi
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Daruko awon ohun elo idana
ii.Salaye bi a n se lo awon ohun elo idana ninu
asa igbeyawo
iii. Jiroro nipa ohun ti okookan duro fun
iv. Dahun ibeere lori eko yii
LitOwe to suyo ninu Itan apenilekoNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Sålåyé itumo owe
ii. Soro nipa orisisi owe åti won
iii. Fa owe yo nibi abala iwé kika
iv. Jiroro nipa anfaani owe.
v. Dåhun beere lori eko
5EdeOnka Yorübå lati
igba dé öodunrun (200-300)
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Tesiwaju ninu kika onka
ii. Ka onkå låti igba dé oodunrun
iii. Se aropo åti ayokuro onkå
iv. Se isodipupo onka
v. Dähun lbéere Iori ekö yii
AsaÄIåyé Iori åwon ohun idåna låyé åtijö
åti ode-oni
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. So iyato laarin ohun élo idåna låyé åtijo åti
ode-oni
ii. Wo Iyato laarin igbéyåwo ayé åtijo ati ode-oni
iii. Dahun ibeere lori eko yii
LitKika lwe litireso ti Ijoba yanNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Ka iwé nåå fifinra won
ii. Fa koko inu ltån nåå
iii. Fa åwon oro tuntun inu iwé naa yo
iv. Salaye awon eko inu iwe naa
v. Jiroro nipa åwon ede-itan
vi. Dahun Ibeere lori eko yii
6EdeOro ise onisilebu meji
_Apeere: duro, jeun, ranju abii
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Sålåyé ise ti oro-ise n se ninu gbolohun
ii. Lo oro-ise ninu gbolohun
iii. Fa oro-ise yo ninu gbolohun
iv. Dahun ibeere lori eko yii
AsaOrin ibile ati iwulo wanNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Salaye kinun nipa orin ibile
ii. Se akojo awon orin ibile
iii. Jiroro nipa iwulo /pataki orin ibile
iv. Dahun ibeere lori eko yii
LitOrisirisi owe Yoruba_ Apeere:
Owe ikilo, alaye, imoran, ibawi, isiti,
abii
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Salaye kini owe
ii. Menuba pataki/iwulo owe lawujo yoruba
iii. idi to Yoruba fin powe
iv. Jiroro nipa eko ninu owe
v. Dahun ibeere lori eko yii
7Idanwo ranpe
Ibewo åwon obi
Isinmi Idaji såå keji
Idanwo ranpe
Ibewo åwon obi
Isinmi Idaji såå keji
8EdeLilo oro-ise keekeeke onisilébü meji ni
gbolohün
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Se åkojo awon oro- onisilebu méji
ii. Lo wön ni gbolohün
iii. Da oro-ise onisilébu meji mo ninu gbolohün
iv. Dåhün ibeere lori eko
AsaOhun élo fun oge sise laarin åwon
obinrin åti Imura. -Äpeere: osun,
ådi-ågbon, lååli, pse dudu, abbi.
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Dåruko awon ohun élo oge sise
ii. Sålåyé bi a se n l0 ökoökan fun sise ara oge
-Jiroro nipa bi a se n se awon ohun wonyi
ose-düdü, ådi-ågbon, osün, abbl.
-Dåhün lbééré lori eko
LitOriki idile- Didåruko oriki Idile kan åti
ålåyé åwon koko
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Sålåyé oriki ldile
ii. Dåruko orisirisi oriki Idilé, bi åpeere: –
oIöfå, areese, Onikoyi
iii. Se itüpale oriki Idile kökan
iv. Fa koko ti o suyo ninu oriki yo
v. Menuba pataki/lwulo oriki idilé
vi. Dahun ibeere lori eko yii
9EdeIjiroro ati ariyanjiyan lori Iyawo kan
dara ju Iyawo méji lo
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Jiroro nipa imo ateyinwa
ii. Tälé ilånå äti ogbon åroko alåriyånjiyån —
lfaara, IPinro, ero, ede äti igünle.
iii. Ko åroko tö gbåmuse Iori ori-örö
iv. Dahun Ibeere lori ekö
AsaOye ni Yoruba Äpeere: Otunba
Balogun, Asipa, Lisa, Basorun, abbl.
lse ti awon Oloye kookan n se
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Jiroro nipa asa oyé jije
ii. Salayé patåki oyé nile Yorubå
iii. Darüko orisi oye ti an je nile Yorubå
iv. Ranti awon ohun elo oye jije
v. Jiroro nipa åwon ami ti a fi da oloye mö.
vi. Dåhün ibéére Iori eko
LitÄwon Oünje Yoruba Åti agbegbé wonNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Sålåye påtåki ounje
ii. Dåruko orisi ounje ti a Iori ni agbégbé koökan.
iii. Se atotonu nipa bi a ti if se Oonje wonyi
iv. Jiroro nipa iwülo Ounje kakan låra
v. Dahun Ibeere lori eko
10EdeAkayé – Kiko oro titun ati didahun
Ibéere låbe akayé
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Ka Iwé ni åkågbådun åti åkadånmuran
ii. Fa awon oro tuntun ninu ekö yo
iii. Sålåyé åwon koko ti o jeyo
iv. Dåhun Ibéére lori eko
v.
AsaEkunrere alaye lori ojuse awon oloye
laarin ilu _ Apeere: Balogun ni olori
awon jagunjagun
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Soro nipa oye ti won n je ni ilu kookan
ii. Salaye ipo ati ise ti o wa fun oloye kookan bi
Apeere: Balogun ni olori awon jagunjagun
– Oluawo- olori awon awo
-Oluode/ Balode -olori awon ode
-Iyalode-olori awon obinrin ilu
iii. Dahun ibeere lori eko yi
LitKika iwe literaso apileko ti ijoba yanNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. So nipa onkowe yi
ii. Salaye itan inu iwe naa ni soki
iii. Jiroro nipa awon koko ti o suyo ninu itan naa
iv. Menuba awon asa ati ise Yoruba to farahan
ninu iwe naa
v. Dahun ibeere lori eko yii
11EdeÄroko Alålåyé iti ilånå -Äpeere:
Bi mo ba di Gominå ipinle Mi.
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Sålåyé nipa åroko alalaye ati llanå
ii. Jiroro nipa ori-oro to jemo åroko alålåyé
iii. So nipa bi a se ko aroko alålåyé
iv. Ko oro Iori ori-örö åroko alålåyé.
v. Dahun Ibeere Iori
AsaOriki åwon oba Yorubå – Äpeere
-Alåäfin ti Oyo
-Ooni ti llé-lfe
-Soun ti Ögbomöso
-Olofå ti öfå
-Olokukü ti ökukü
-Orångün ti Ila
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Dåruko åwon oba alådé Yorübå
ii. Ilu ti won joba le lori
iii. Dahun Ibeere lori eko
LitAwon orin ibile ni agbégbé köokanNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Dårüko åwon orin agbégbé kookan
ii. Salaye igba ati akoko ti won ma n ko Orin naa.
iii. Jiroro nipa iwulo awon orin wonyi.
iv. Dahun ibéere lori eko

12Atunyewo eko lori ise saå yii lori édé, åså åti litirésö
13Idånwo såå keji

Primary 5 Third Term Scheme of Work for Yoruba Language

   
 CLASSPrimary/Basic 5
 SUBJECTYoruba
 TERMThird Term
WEEKTOPICSLearning Objectives
1Idanwo Ranpe fun ibeere saa tuntunNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Rånti gbogbo Imo ateyinwa lori eko yii
ii. Won yoö le mo åsise won ati onå åbayo
2EdeÅroko AlariyanjiyanNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Sålaye iru åroko ti åroko alariyanjiyan jé.
ii. Da llånå kiko aroko yi mo,
iii. Ko apeere ori pre fun åroko yii.
iv. Dåhun Ibeere lori eko
AsaEre Ayo
Awon to n taa,ohun ibi ti won ti n faa
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Salåye ere ayo gege bi okan låra ere idéraya.
ii. Irüfe åwon to n ta ere ayo.
iii. Dåruko ohun elo ere
iv. Salaye ibi.ti won taa iti Åkoko
v. Dahün ibeére lori eko
LitOwe to suyo ninu itan arooso ati oro
geere
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Fa awon owe to suyo ninu åwon lwe itan åroso
ii. Sålåyé okookan awon owe wonyi,
iii. Iru öwé ti won je åti bi won se loo won ninu
awon itan nåa. ninu åwon itan naa
iv. Lo won ni gbolohün låti fa itumö won
v. Déhün ibééré Iori eko yii
3EdeOro oruko afoyemo ati alasikaNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Sålayé oro oruko afoyemo ati alaiseéka.
ii. Se akojo apeere awon oro oruka wonyi
iii. Lo apeere won yi ni gbolohun lati fi itumo
won han
iv. Ise ti won n se ninu gbolohun
v. Dahun lbééré Iori ekö yii,
AsaOkoto tita.
Ohun élo re, iye åwon to n ta a
Anfaani ati åléebü eré
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Sålåyé ere okoto dåadaa.
ii. Såpéjuwe åwon ohun élo eré yii.
iii. Dårüko iye åwon to n ta okoto.
iv. Sålåye anfaani ati aleebu ere okoto.
Litise eré onise kekeré lati ko omode
lögbon.
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Se agbekale eré onise kékeré kan.
ii. Fa ogbon inü ere naa yo.
iii. Ka eré nåa ni åkågbådun.
iv. Dåhün ibééré lori ere naa.
4EdeOro oruko Aseeka ati oro oruko
aridimu
Lilo won ninu gbolohun ede Yoruba
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Sålåyé ki ni oro oruko Asééka åti Aridimu jé.
ii. Se åkojo åpeere fun awon oro oruko wonyi.
iii. Lo åwon apeere wonyi ni gbolohün kikun.
iv. Dåhun ibeéré Iori eko yii
AsaEre Arin
Bi a n se se ere naa
-Ofin ere naa
-Anfaani ati aleebu ere naa
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Salaye ere arin
ii. Bawo lan n se ere yii
iii. Eniyan melo lon n se ere yi
iv. Daruko ohun elo fun ere yi
v. Akoko ti n se ere yi
vi. Ofin ere arin
vii. Salaye anfaani ati aleebu ere yi
viii. Dahun ibeere lori eko yi
LitItan Aroso
Awon owe ati akanlo ede to suyo ninu
itan aroso naa
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Da itan aroso naa
ii. Salaye koko inu itan naa
iii. Fa awon owe ati Akanlo ede to suyo ninu itan
naa yo
iv. Lo awon akanlo abe itan aroso naa
v. Dahun ibeere abe itan aroso naa
5EdeAkanlo Ede -Awitunwi
afiwe pan-na , oyin, ayo abii.
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Salaye kini awitunwi afiwe oro pan-na –
oyin ayo, ife abii
ii. Daruko awon akanlo ede miran bi assodun
asoregee ati awon akanlo-ede miran
iii. Wa itumo fun oro won yi
iv. Lo won ni gbolohun kikun
v. Dahun ibeere lori eko yi
AsaIse ajumose lawujo Yoruba
Itumo ise ajumose-Apeere: ise ona yiye,
ile kiko, ebe kiko, epo fifo abii
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Salaye kini ise ajumose ati iha ti awon Yoruba
ko si
ii. Daruko awon ise ajumose laarin awon Yoruba
i.e ona yiye
iii. Menuba iwulo ise ajumose ati alebu re
iv. Dahun ibeere lori eko yi
LitKika iwe ewi apileko ati ijoba fowo siNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Ka ewi ni akagbadun lai ko won lenu
ii. Da ilana ti a n gba ko ewi mo/mo abuda ewi
iii. Fa awon ona ede inu ewi yii yoo
iv. Salaye awon ona ede wonyi ni ibamu pelu bi
won se lo wan
v. Dahun ibeere lori eko yi
6EdeOro aropo, oruko ni ipo oluwa
-ise ti oro aropo nse
eyo ati opo
-idamo kookan ati ilo wan
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Salaye oro aropo oruko ninu gbolohun Yoruba
ni ipo oluwa
ii. Fala si oro aropo oruko nidi nipo oluwa ninu
gbolohun
iii. Sapejuwe oro aropo nipo eyo, opo ati nipe
oluwa
iv. Lilo won ni gbolohun kikun
v. Dahun ibeere lori eko yi
AsaAanfaani ati alebu ise ÂjùmoseNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Sàlàyé awon anfaani to wa ninu ise ajumose
ii. Yoo le so awon aleebu ise ajumose
iii. Dahun ibeere lori eko yi

Lit Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Ka iwe na ni àkàgbadun
ii. Salaye ibi kika naa
iii. Fa koko inu iwe naa yo
iv. Salaye eko ti a ri ko ninu iwe naa
v. Dahun ibeere lori eko yi
7Idanwo ranpe
Ibewo åwon obi
Isinmi Idaji såå keta
Idanwo ranpe
Ibewo åwon obi
Isinmi Idaji såå keta
8EdeOrò arôpò orüko ni ipo àbo ati ìlo won
ninu gbolohun.
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Se ëkunrere alayé lori oro aroPò oruko.
ii. Sàpèjüwe oro aroP0 ni ipò àbò ninu gbolohun.
iii. Menu ba orisi ona miiran ti à gbà lo aropo
ninü gbolohùn.
iv. Pinpin àwon akekoo si owoowo lati se asepo
ise.
v. Dahun ibeere lori eko yi
AsaEré ìdérayi.
Eye mélò tolongo waye.
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Sàpèjüwe eré Idiraya pelu apeere.
ii. Sàlàyé bi a se ri se eré Eye melo tòlòògo waye.
iii. Déruiko ohun èlò eré
iv. Mënuba ìwülò eré yìi.
v. Dahun Ibeere Iori eko yii
Litkika itàn àroso olooro wuuru.
Fa akanlo ede ati asa Yoruba inu itan
naa yo
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Ka ìtàn nâà ni àkàgbddun àti àkajagaara.
ii. Fa awon akanlo ede inu itan naa yo
iii. Daruko awon asa Yoruba to suyo ninu itan na
iv. Salaye koko eko ti ri ko ninu itan naa
v. Dahun ibeere lori eko yi
9EdeOro Aroso oruko ni ipo eyan ati ilo re
ninu gbolohun
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Salaye oro aropo oruko ni ipo eyan
ii. Da oro aropo to n sise eyan mo ninu gbolohun
iii. Salaye bi n se lo oro aropo gege bi eyan ninu
gbolohun
iv. Dahun ibeere lori eko yi
AsaEre idararaya-Boju boju
-Bi won se se ere na
-Awon wo lo n sere
– Igba ati akoko
-Ofin ere na
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Salaye ere idaraya yi pelu apeere
ii. Sapejuwe ohun elo ere yi
iii. Menuba awon ofin ere yi
iv. Igba ati akoko ti a maa se n ere yi
v. Salaye anfaani ati aleebu to wa ninu ere yi
LitÄkänlo ede pelu itumo won ninu
gbolohün édé Yorubå.
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Salaye itumö åwon åkånlö édé.
ii. Lo Wön ni gbolohün kikun.
iii. Pipe åwon akeeko Iokökanlati lo åkanlo edé
ni gbolohun.
iv. Kiko koko ise sile sinu’ iwé wan.
10EdeOro Atökün:
itumo,lrisi ati lilo ni gbolohun.
Sise akojo öro atokun.
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Sålåyé orö atökün pelu apeere.
ii. Sise åkojo oro atokun to wa ninu ede Yorübå.
iii. Lilö ninu; gbölohün kikun
iv. Dahun ibeere lori eko yi
AsaItumo awon owe ninu ede YorubaNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Se akojo owe lorisirisi ona
ii. Salaye itumo won/itan ti won ti jeyo
iii. Lo owe kookan ni gbolohun kikun
iv. Salaye iru owe ti won je
v. Dahun ibeere lori eko yi
LitEwi aro pelu Itupale re ninu kilaasiNi opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Ronu jinle lati se gbekale ewi aroso
ii. Ka ewi aroso ni akaye ati akagbadun
iii. Fa awon ona ede tabi ewa ede inu awon ewi
na yoo
iv. Salaye bi won se lo awon ona ede inu ewi naa
v. Dahun ibeere lori eko yi
EdeIlo örö oruko ninü gbolohun édé
Yorubå .
-Didamo orisirisi oro oruko ati ise ti
won n se ninu gbolohun.
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Salaye oro oruko ,ki ni oro oruko?
ii. Bäwo la se då örö oruko mo ninu gbolöhün
édé Yorübå.
iii. Dåruko orisirisi oro oruko to wå åti ise ti won
se ninü gbolohün (oluwa,åbo åti Eyån).
iv. Dahun Ibeere lori ekö
AsaOge sise laarin awon okunrin ati afiwe
oge sise laye atijo ati tode oni
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Tesiwaju ninu önå d awon okunrin wa fi n soge.
ii. Dårüko orisirisi åsö,filå ti åwon babanla wa
ri gbå soge.
iii. Akoba ti ölåju mu bå asa oge sise.
iv. Ijora ati lyatö laarin oge sise laye åtijö ati
öde-oni
v. Dåhün ibeere Iori eko yii
LitÄgbeyewo itån oloro geere/Wuuru pelu
atupale re
Ni opin Idanilekoo, åwon akekoo yoo lé:
i. Ka itån naå ni åkågbådun
ii. Se atunpale itån nåå
iii. Wa itumo si åwon oro tuntun tö suyo ninu
itan nåå
iv. Dahun ibeere lori eko yi
12Atunyewo eko lori ise saa lori ede, åså äti literésö.
13ldånwo säå ket

Professional Certification

CIBN Syllabus

CITN Syllabus

APCON Syllabus

Company

Career

Media Kit

SyllabusNG

© 2024 Created with Page 5 Digital
Download Syllabus