Primary 4 Yoruba Language Scheme of Work

Download the Unified Basic 4 Scheme of Work for Yoruba Language to serve as a guide for educators and primary school teachers

Home » Primary 4 Scheme of Work » Primary 4 Yoruba Language Scheme of Work

About Yoruba Language Scheme of Work for Primary 4

Yoruba is a subject designed to draw the pupils closer to their culture and tradition. This subject educates them about their indigenous language in a formal setting highlighting the importance of the Yoruba language and culture in the community . They will be taught to put what is being spoken at home in writing and they will also know how to read them.

The scheme for this class covers various aspects such as; The principles of good conduct, Yoruba folklore, analyzing characters and themes in folktales and appreciating value, traditional festivals, praise poetry, traditional Yoruba music and dance form, comprehension skills and developing fluency in written expression.

The educator should communicate in Yoruba to the pupils while teaching them and the pupils should be encouraged to do the same. This will enhance the fluency of the language being taught. 

Download Primary 4 Yoruba Language Scheme of Work

primary4-yoruba

Know what’s expected of you as an educator

Download the Lagos State Unified Scheme of Work for Primary 4 Yoruba Language

Primary 4 First Term Scheme of Work for Yoruba Language

LAGOS STATE GOVERNMENT MINISTRY OF EDUCATION UNIFIED SCHEMES
OF WORK FOR PRIMARY SCHOOLS
Yoruba Scheme of Work for Primary/Basic 4
 CLASSPrimary/Basic 4
 SUBJECTYoruba
 TERMFirst Term
WEEKTOPICSLearning Objectives
1Idånwö rånpe fun Ibere Såå tuntunIdånwö rånpe fun Ibere Såå tuntun
1EdeÖnkå åtisorö YorübåNi opin idanilokoo, awon akekoo yoo le
i. Salaye iye féresé to wå ninu yårå ikåwé
ii. So itumo onka ati ati isoro lede Yorübå
iii. Ka onka lati 0okan fifi dé ogoji.
AsaIwa OmoluabiNi opin idanilokoo, awon akekoo yoo le
i. Sålåyé iwå omoluabi B.a. ‘lbåwi, ikinni, igbowofagba,
siso otito, hihu iwa pele abi
ii. Kiko orin iwå omoluabi kan Bi åpeere: Je Omo Rere-
ii. Dåruko åwon iwå ibåje låwüjo, bi 0le jija, iro pipa,
iwå ijinigbe, Ipaniyan, iwå jägiijägan, abbi.
LitKika Iwe Itan Aroso:
Ayänfe omo ôrukän.
Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le
i. ka iwe literaso ni akagbadun
ii. Fa äwon kóko inú itan náä yo
iii. Säläyé äwon iwä ědě inú’iwé na.
2EdeApeko
Pipe oro oniisilébů méji, méta,
m’erin äti márůnún
Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le
i. Ka äwon oro apeko tó wä Iójú pátákó ikowe ti äpeere:
oro onisillebu méji, m’eta, meran abbi.
ii. pin si owoowo lati sagbeyewo awon oro apeko
iii. Ko oro onisilebu merin ati márůn-ún
AsaEko äti sise ilé láwůjo YorůbáNi opin idanilokoo, awon akekoo yoo le
i. Dárúko orisi ise ilé sise n’ilě Yorůbá. B.a: aso fifo,
ile gbigbá, ata lilo, abbi.
ii. Säläyé äwon onä ti ä ó gbä se ämúlö’eko ile, bi ikini,
ibowo fâgba, ltoJu ile, abbi.
iii. Se ere onîse kekere ti Ó sâfihăn eko-ile.
LitKlka’iwe Lîtireso ti ijoba yanNi opin idanilokoo, awon akekoo yoo le:
i. Fa âwon koko oro tó suyo ninu itan na.
ii. Sâlăye âwon ti o wâ nînó ăwon literaso alohunwon yî
(B.a isinję, imura idan pâpa)
3EdeAmi ldamo n’inó girama (Apă kinni)Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le:
i. Salaye itumo âti idamo ninu giramâ
ii. Dăruko orisi ămi idamo ati łwulo okookan won
b.a. Ami idânudóró(.) Amii Iyanu (!), âmi ibeere(?)
âmi Semi Koloonu(;) âmi kolonu(:) ami akamo onigun,
ammi akamo oroto abi.
AsaAså’igbéyåwo n’ile YorübåNi opin idanilokoo, awon akekoo yoo le:
i. Sålåyé’itumo igbéyåwo nile Yorübå
ii. Dåruko orisi igbéyåwo ti owå (b.a. ‘igbéyåwö ibile,
sosi, masalaasi ati koöti)
iii. Salaye awon igbése ti o wåyé ninu igbéyåwo.
bi åpeere: ifojusode, Ijohen, itooro abbi.
LitKika iwe Aroso:
Ayanfe Omo Örukån.
Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le:
i. Ka iwé litiréso ni åkågbådun
ii. Fa åwon koko inu itån nåå yo
iii. Salaye awon iwå ödé inu iwe nåå.
4EdeIfesiwaju nipa Armi idamo ninü g’iråmåNi opin idanilokoo, awon akekoo yoo le:
i. Sålåyé årmi’idåmo ninu giramå åpeere
ii. Ami åyolo komå oloke onibeji(” “), ami aopo (-),
ami akamo().
ii. ohka si awon ami to se pataki ti won ma n gbeyin oro
ninu gbolohun
iii. se idamo won ninu gbolohun nipa sise awon ise won yi
AsaAnfani iwa omoluabi ninu ile ati awujoNi opin idanilokoo, awon akekoo yoo le
i. se ere nise to gbe iwa omoluabi han
ii. won ko orin to jemo iwa omoluabi
iii. piran si owoowo lati salaye anfaani iwa omoluabi
iv. toka si ihuwasi akeeko to safihan iwa omoluabi
LitEya LiterasoNi opin idanilokoo, awon akekoo yoo le
i. salaye ohun ti literaso je
ii. daruko orisi eya lireraso lede yoruba
iii. salaye pataki awon eya awon literaso won yi
5EdeOhka ati Isiro Yoruba låti ogoji – ogorun-unNi opin idanilokoo, awon akekoo yoo le
i.Ka onka lati ogoji dé ogorün-un
ii.Töka bl onka se ri lé ati din.
iii. Ka iye åga ijoko ni kilååsl
AsaIgbéyåwo åti åwon ohun idånaNi opin idanilokoo, awon akekoo yoo le:
i. Salåyé pataki ohun Idåna nibi Igbéyåwo
ii. Daruko orisi awon ohun idana bi isu, obim ataare,
orobi abi.
iii. salaye ihulo awon ohun idana nibi igbeyawo
LitItesiwaju lori ohu ti literaso jeNi opin idanilokoo, awon akekoo yoo le
i. Se alaye kikun nipa eya literaso yoruba
ii. daruko ona ti wan pin si
-Alohun ati apileko: Alohun pin si ewi, ere onise ati itan
aroso
-Literaso apinleko pin si: Itan aroso oloro geere, ewi
apileko, ere onitan apileko
6EdeIsori oro lede yoruba
Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le:
i. fun isori oro ni oriki
ii. daruko isori oro lede yoruba Bi apere: oro oruko,
oro ise, oro apejuwe, oro aponle.
iii. salaye ipaa ti okookan ko ati iwulo wan ninu gbolohun
ede yoruba
AsaIwulo eko-ile ati ise eleNi opin idanilokoo, awon akekoo yoo le
i. Jirorö nipa åwon ise ilé
ii. såläyé påtåki ikini åti iböwofågbå Iéwüjo
iii. Dåruko åwon önå ti a n lo lati toju ayika wa.
LitKika Iwé ewi ipilekoNi opin idanilokoo, awon akekoo yoo le:
i. Da ka Iwé nåå fun ra won ni Iyårå ikéköö
ii. sålåyé åwon åså åti ise Yorubå ti o suyo ninü Iwe
litirese åpileko
7Idanwo ranpe Ibewo / Isinmi
ìdajì saa
Idanwo ranpe Ibewo / Isinmi ìdajì saa
8EdeAroko kikoNi opin idanilokoo, awon akekoo yoo le:
i.So oriki àroko
ii.Salaye llanà àti ogbôn ti a n ta fun àròko kiko
iii.So orisirisi aroko ti o wa. Bi àpeere, àròko alapèjuwe,
oniròyìn, alalàyé, abbl.
AsaIwà Omoluàbi
(Ere ti o fi ìwa omoluàbi hàn)
Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le:
i.Sàpejuwe ìwà omoluabi
ii. Se àrojinle lor;i ìwà omoluàbi
iii. Se ere onise to da Iori ìwa omoluabi lawujo
LitKika ewi ÄpilekQ.
OBINRIN NI MI
Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le
i. Ka/ko ewi to da Iori oblnrin
ii. så!åyé påtåki obinrin Iåwujo
9EdeArokq Asapejuwe
Oünje ti mo férån
Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le
i. sålåyé iru årokö ti a n pe ni aroko asapejuwe
ii. Jiroro nipa åwon ohun
iii. Ko aroko asapéjuwe lori ori ti won yan
AsaAfiwé Igbéyawo ibile åti
Igbéyäwö söösi åti massalasi
Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le
i. Jiroro nipa ijora laarin igbeyawo ibile åti
Igbéyäwö söösi åti massalasi
ii. salaye ipa awon igbeyawo yi lawujo
iii. tooka si iyato laarin igbeyawo ibile, söösi åti massalasi
iv. salaye ipa awon igbeyewo yii lawujo
Lit
Kika ewi apileko ti ijobâ yân
Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le
i. Le ka itân inu iwe naa
ii. Tumo âwon oro ti o ta köko.
iii. Jıroro nıpa âwon onâ-ede
iv. Dâhûn âwon ıbeere ti o’ jeyo
10EdeÂpeko – oro Onİsilebu merin,
mârun-un atimefa
Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Ko âwon oro onısılebu marun, rrıârün lâti ojü pâtâko
İkowe
ii. Ko apeko awon oro ti oluko pe fün won. Bı apeere::
Aânu, Adeboye, Kâbiyâsi, Ajântaâla, Arİkuyerİ, abbi.
AsaÄfiwé Igbéyåwo kootü, soosi ati
Måsalaasi
Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Sålåyé kikin nipa påtåki Igbéyåwö Köotu, soosi ati
Måsalaasi
ii. Dåruko ilåna to rö må Igbéyåwo yi
iii. Jirörö nipa Iyåtö Iåårin åwon Igbéyawo nåa.
LitEwi apileko lori eniyän ni mlNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i.Sålåyé kikin nipa ohun ti éniyån
ii. Ko orin enikéni ti ba’ nipa fe Irånlöwö fun’
ii. Dahun Ibeere ni abala yii.
11Atunyewo awon ise Saå yiAtunyewo awon ise Saå yi
12lgbâradi fün İdânwo saâ kinilgbâradi fün İdânwo saâ kini
13Idanwo saa kin-ın-niIdanwo saa kin-ın-ni


Primary 4 Second Term Scheme of Work for Yoruba Language

   
 CLASSPrimary/Basic 4
 SUBJECTYoruba
 TERMSecond Term
WEEKTOPICSLearning Objectives
1EdeIdanwo ranpe fun ibeere Saa KejiIdanrawo Ranpe fun ibere såå keji
i. Äwon akekoo mu gbogbo åwon ékö ti won ti
ko ni såå ti o kojå wa Si iranti won
AsaAtünyewo ise saa kiini
lori ede, asa ati litireso.
Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le::
i.rånti åwon eko ateyinwa
ii. jiroro lori ohun ti o ye won ninu eko éteyinwa
iii. beeré ohun ti ko ye won
iv. dåhün ibééré Iori åkori eko
LitAtünyewo ise saa kiini
lori ede, asa ati litireso.
Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i.rånti åwon eko ateyinwa
ii. jiroro lori ohun ti o ye won ninu eko éteyinwa
iii. beeré ohun ti ko ye won
iv. dåhün ibééré Iori åkori eko
2EdeOro ati idakejiNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. so Itumö oro åti idåkeji
ii. salaye bi Idakeji oro sen wåyé
ii. Lo oro ati idakeji ni gbolohün kåkåni
iv. fa ilå si abé åwon oro tö jé idåkeji sira won.
AsaIlu liluNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Ki oriki ilu ni soki
ii. Darüko orisi Ilu ile Yorubå.
iii. Salåyé iwülo ilu lilü lawujo wa
LitÄlo pipaNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Fun alo ni oriki alo tin alo n je
ii. Dåruko orisi alo to wa
iii. Sålåyé iwülo ålo.
3EdeOruko osu nini odünNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Sålåyé åwon osu to wa ninu odün
ii. Daruko åwon oruko osu naa
iii. Rånti åwon ohun to se påtåki ninu awon naa
iv. Se åmulo oruko naa ledé Yoruba
AsaIlu ati iwulo reNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Sålåyé åwon ilu ti n alü fün onså köokan
ii. Dåråko åwon ti å lü nibi ayeye
iii. Jirdrd nipa ijo ati orin ti å ko nibi ilü kökan.
iv. So bi a se lé fi soro
LitÅlö ÄpagbéNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Fün ålö åpagbé ni oriki
ii. Se äkojo ålo onittan/åpagbé
iii. Fa eko ninu ålö köokan yo.
4EdeAwon ojo ose ni ede YorübaNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Dåruko åwon ojo to wa ninu ose.
ii. So bi a nsee pe awon ojo wonyi
iii. Salåye Idi/itan to ro mo awon ojo wonyi
iv. Jiroro nipa igbagbo Yorüba nipa åwon ojo wonyi
AsaOrisii ijo ti å n jo si ilu kookanNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Såpéjuwe bi a fe ri gbowo ijo lati ba ilü mu#
ii. Salaye bi a ee Ie gbese låti bå mu
iii. Se åpeere kikün Iori bi å se 1o gbö ilu.
LitArofé KikåNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Sålåyé kikon nipa oriki arofö
ii. so nipa bi a gbohun soke sodo ninu arofo
iii. Jiroro nipa koko ti o jeyo ninu arofo.
5EdeOna ti an gbe se ibeereNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Daruko àwon a n gba se ìbeere
ii Sàlàyé lekunrerë nipa awon wunren ôsegbere.
ii. Se oniruuru apeere èrë a;òbéèrò,
Asa
Iwulo ilu lilù nilë Yorùba
Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Salaye bi kòkan se ri ni ìrisi ati àpèjuwe
ii. Daruko àwon ìlù,
iii. Safaye awon ohun ti ari lo ìlù fin.
iv. Dahùn àwon ìbéèrò lori eko yi
Lititesìwaju eko Iori arofe gigùnNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i Salaye ohun ti arofo je
ii. Se akojopo orisi àròfo.
iii, Fa àwon koko inu àròfè yo.
iv. Ka àròfò jade.
6EdeÂwon onà ti à n gbà se ìbeereNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Sàlàyé nipa ìmò àteyìnwé
ii. Darüko àwon atôka wunren asebeere.
iii. lo awon wunr en atoka asebeere ni gbolohûn.
ASaiwülo ìlu lilu Iawùjo YorubaNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Sàlàyé pataki ilu lilu lawûjo wa
ii. Daruko isê ti ilu n se, bi àpeere: Idârayâ, ìtüfò, ogun,
iii. Âayé kikün lori awon koko.
LitItan AkonilogbonNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Salaye awon itan akonilogbon
ii. So nipa awon ogbon towa ninu itan
iii. Fa awon eko inu itan yo
iv. Jiroro nipa awon koko inu itan
7
Idanwo ranpe Ibewo / Isinmi
ìdajì saa
Idanwo ranpe Ibewo / Isinmi
ìdajì saa
8EdeAkanlo EdeNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Fun akanlo ede ni oriki
ii. Se atoju akalo ede
iii. Wa itumo si awon akanlo ede
iv. Lo awon akalo ede ni gbolohun
v. Salaye iwulo akanlo ede
AsaAso wiwo laarin okünrinNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Salaye/daruko awon aso wiwo laarin okunrin.
ii. Pin aso si Isori mejl: iwole ati imurode
iii. Jiroro nipa iyatö låårin aso iwole ati imurode
iv. Rånti påtåki aso wiwö.
v. Dahun Ibeere Iori ekö
LitÄröfo Iori iwå rereNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Salaye ki ni iwå rere.
9Ede
Itesiwéjü ninå oro åti idäkeji
Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Salaye Imö ati ateyinwa
ii. Se åkojo orö ati idåkeji won
iii, Lo åwon oro wonyi ni gbolohun.
iv. So itumo åwon oro naa.
AsaOruko AbisoNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. So itumo oriki oruko abiso
ii. Se akijopo oriki abiso
iii. Salaye okookan oriki abiso
iv. jiroro nipa pataki oriki abiso
LitIwe kika AkayeNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Ka iwe literaso yi fun ran won ni iyara ikawe fun etigbo
awon elegoo ati elegbe won
ii. Salaye awon koko ti ibi ti won ka da lori
iii. Wa itumo si awon oro tuntun ti o suyo nibi ti wan ka
iv. Dahun ibeere lori ibi ti won ka naa
10EdeAroso Akotan tabi oniroyinNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Fun owe ni oriki
ii. Daruko orisirisi owe to wa
iii. Se atikoju awon owe
iv. Salaye ohun tin alo owe fun
AsaImura löde-öniNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Salaye onå imura låyé ode-oni
ii. Dåruko åwon orisirisi aso ode-oni.
Bi åpeere Seeti, Gåün.
iii. Äfiwé aso åtijö åti ode-oni
iv. Wiwa onå åbéyo si isoro aso wiwo Iode oni
LitAlo ApamöNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Sålåyé nipa ålö apamo.
ii. Se åkpjo alo apamo
iii. Jiroro nipa koko in ålö åpamo.
iv. So iwülo ålo apamo.
v. Dåhun ibéeré ti o je
11Agbeyewo ise saa keji Iori Edé, Äså
ati Litirésö Yorübå
Agbeyewo ise saa keji Iori Edé, Äså ati Litirésö Yorübå
12Agbeyewo ise saa keji Iori Edé, Äså
ati Litirésö Yorübå
Agbeyewo ise saa keji Iori Edé, Äså ati Litirésö Yorübå
13Idänwd såå kejiIdänwo såå keji

Primary 4 Third Term Scheme of Work for Yoruba Language

   
 CLASSPrimary/Basic 4
 SUBJECTYoruba
 TERMThird Term
WEEKTOPICSLearning Objectives
1EdeIdanwo ranpe fun ibeere saa tuntunNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i.Gbaradi fun ise saå tuntun
ii. Ranti åwon eko ti won ti ko ni såå o koja
AsaAtunyewo eko lori asaNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Rånti gbogbo imö åti eko ateyinwa
LitAtunyewo eko nipa literasoNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Råntå gbogbo imö ati åteyinwa.
ii. Nå imö kikun
iii. Dahun ibeéré Iori ohunti won ko
2EdeOnkà Yorûbâ –
Ogorun-un – Ââdojo (100-150)
Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Sàlàyé ilàna ti a n gbà ka ònkà Yorubâ:
ii. Ilana ilopo
iii.llana aropo
iv. Ilana ayokürò
v. Ka onka lati ogôrûn-un de aadojo
AsaOrikì Orilë ati itumo reNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Sàlàyé ohun orikì orilë jê
ii. Darüko orisìi orikì orilë kòokan
iii. jiròrò nipa koko ti o je yo ninü orikì orilë.
iv. Sàpèjuwe ìyàto Iaàrin oriki orile kan si ìkeji.
Lititan Akoni: Balogun ibikunléNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i.Salayé nipa ìtan igbési ayé Balogun ibikünlé
ii. Darüko ìlü ti ati bi Balogun ibikünlé
iii. So nipa ișę rere ti okunrin naâ șe,
3EdeÔnkâ Yoruba:
aadojo dă igba (150-200)
Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Ka Ônkâ lăti aadojo de igba (150-200)
Îi. SâIâye bi a șe Io âmi Îsędipupo, ayokuro âti âșopo
iii. llânâ onkâ âdăyeba âti ode-oni.
AsaÂwon ohun ti o un farahân ninu
oriki orîlë
Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Sâlâye ki ni oriki orilë.
ii.Dâruko oriki orilë âti iran kookan
iii. Răntî âwon ohun ti ri fojóhân nînu âwon oriki orilë
iv. menuba pataki ati i owulo oriki onile
LitItan Akoni Herbert MacaulyNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Sâlâye ‘ltân igbosi aye akoni yii
ii. Oodun ti a bi Herbert Macauly
iii. Sàlàyé àwon ise rere ti o se
iv. jiroro nipa awon ohun ti o so arakunrin naà di akoni.

4EdeOro OrukoNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. fun oro oruko ni orikì
ii. Sàlàye ëya oro orüko bi àpeere: Âridìmü, afòyemò,
aseeka, alafiseeka, orüko ibìkan, abbi.
iii. Ko apeere oro orüko kòkan
iv. Menuba abùdâ oro orüko àti ise won
AsaKiki Oriki OrileNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Ki orikì onile ìran kookan
ii. Sàlàyé koko tô joyo ninu orikì kookan
iii. So nipa ìtan to ro mo orikì kookan
iv. Toka si eewo iran kookan
v. So nipa ibi ti iran naa
LitItan Akoni Ransome KutiNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Sålåyé itån Igbési aye akoni yii
ii.odün ti abi Ransome Kuti
iii. Sålåye awon ise rere ti o se
iv. jiroro nipa awon ohun ti o so arakunrin nåå di akoni.
5EdeOro Orüko
– Ise ti oro oruko n se ninu gb0lohün
Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Ki eéki oro orüko
ii. Sålåyé ise ti orö oruko n se ninu gbolohun . B.A.
Olüwå, Äbo ati eyån
iii. Pin oro oruko si isori
iv. Ko oro orüko sile
AsaEewo ti aisan mü waNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i, Sålåyé ki ni ééwo
ii. Dåruko orisi eewo to wa
iii. Salaye Ohun to sokunfå eewo wonyi
iv. Pin eewo si isori eewo alian, eewo Imototo, eewo ise,
eewo Iran / Idile
v. Dåhün beere lori eko
LitItan Akoni -Obafemi Äwolowö
Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i, Se åpéjüwe Oloyé Qbåfémi Awolowö
ii. So nipa itån Igbesi ayé 0loyé Obåfémi Awdlowo
iii. Sålåyé ise ribiribi ti okünrin naå nigbå aye re eyi ti o so
o di akoni.
6EdeFifa orö oriko yo ninu gbolohun
édé Yorüba
Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Da örö oruko mo ninü gbolohün
ii. Såpéjüwe orisi orö oruko
iii. Toka si ise ti oro oruko o se nini gbolohün
AsaItumo to o ro mo eewo kookanNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Sålåye åwon ééwo ti aisan mu wa
ii. So nipa ééwö ti o jemo ise kookan
iii. Se åkojo éewo lorisirisi
iv. Daruko eewo fun ìlera titi Imototo
LitItan Akoni Mosudi Olawale AbiolaNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Se àpèjüwe Mosüdì Olawâlé Abiolâ
ii. So ìtàn ìgbési ayé Môsüdì Abiola MKO
iii. Salaye awon isê ribiribi té se nigbà ayé re
iv. Ya àwòrén MKO Âbiola.
7Idanwo Ranpe/lbewo/Olidè ìdaji saaIdanwo Ranpe/lbewo/Olidè ìdaji saa
8EdeAroko OniroyinNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. ki oriki aroko oniroyìn
ii. Sàlayé ìlànà kiko aroko oniroyìn
-Ifaara, àlayé, ìgunle, abbl.
iii. Ko aroko oniroyìn Iori koko oloro kan
AsaEewo ti aisanNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Salaye lori ewo aisan ati idi to o fin je eewo
ii. Tunmo awon eewo wonyi
iii. Daruko awon eewo ti aisan mu wa
LItItan Aboni-MoremiNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Sàpèjuwe Morèmi Ajasoro bi Aboni
ii. Salàyé itan igbesi aye re
iii. So nipa ise ribiribi to se nigba aye re
9EdeAroko AsapejuweNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Ki oriki aroko asapejuwe
ii. Salaye ilana kiko aroko asapejuwe
-ifaara, afaye, igunle, abbi
AsaAnfant ti o wa nibi Pipa ééwo moNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Salaye anfani ti o wa ni bi papa eewo mo
ii. Daruko awon eewo ile yoruba ati ohun ti o ro mo
ewo na
iii. So pataki pipa eewo mo
Litltån Aboni – Efunroyé TinubuNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Såpejuwe aboni obinrin – Efunroyé Tinubu
ii. So nipa Itan Igbési ayé re
iii. Toka si ise ribiribri to se nigbå aye re
-Ya åworan Efunroyé Tinubu

10EdeÄroko Asåriyånjiyån

Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Ki oriki eewo asariyanyin
ii. Salaye ilana kiko aroko asariyanjiyan
– ifara, alaye, igunle abbi
iii. Ko aroko asariyanjiyan lori koko oro kan
ASaÉéwö Iran/iluNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Salaye eewo ilran ati ilu kookan
ii. Såläyé okünfai ééwö naä
iii. So iyipadå to dé bå eewo yi
LitItesiwaju Itan Aboni- Funmilayo KutiNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Såpéjåwe aboni Obirin Funmilayo Kuti
ii. So nipa Itan Igbési ayé re
iii. T’ oka si ise ribiribri to se nigba aye re
-Ya aworan Funmilayo Kuti
11EdeEya Ara FifoNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. ki eéki eyå ara ifo
ii. dåruko åwon eya ara ifo tö wå fun iro édé pipe
iii. pin eyå ara ifö si åsunsi ati akanmole
AsaKiki Oriki Ilu bii Ife, Ékiti, Éko abbl.Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. ki oriki åwon bii Öyo, Ékitl, Éko, abbi.
ii. Salaye awonh koko inu oriki naa
iii. Jirorö nipa åbüdå ilü koökan
LitItan Aboni – Klidlråtü AbiolaNi opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:
i. Sapejuwe aboni obinrin Kudiråtu Abiölå
ii. So nipa Itan igbési aye re
iii. T oka si ise ribiribri to nigbå aye re
-Ya aworan Kudiratu
12Ałunyewo ęko lori ișë saâ ninu
Ëdë, Âșâ âti litłreșo
Ałunyewo ęko lori ișë saâ ninu
Ëdë, Âșâ âti litłreșo
13Akanșe idanwo lori ișę odun yii ninu
Ëde, Âșâ âtl litłreșo
Akanșe idanwo lori ișę odun yii ninu
Ëde, Âșâ âtl litłreșo

Download Primary 4 Yoruba Language Scheme of Work

primary4-yoruba

Know what’s expected of you as an educator

Download the Lagos State Unified Scheme of Work for Primary 4 Yoruba Language

Professional Certification

CIBN Syllabus

CITN Syllabus

APCON Syllabus

Company

Career

Media Kit

SyllabusNG

© 2024 Created with Page 5 Digital
Download Syllabus